Teenagers money ritual: Wo àwòràn ohun tó ṣẹlẹ̀ ní Abeokuta lásìkò ikú Rofiat tí Soliu àti Mustaqim pa

Akojopo ohun to ṣẹlẹ ni Abeokuta titi ọwọ fi tẹ awọn ọdọmokunrin to pa ololufẹ ọkan ninu wọn ree ninu aworan.

Iku Rofiat

Oríṣun àwòrán, BBC/ Family

Àkọlé àwòrán, Rofiat rèé, arewa ọdọmọbinrin ti Soliu àti Mustaqim pa ni agbegbe Adatan ni Abeokuta
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Aro mẹta ti awọn ọdọmọkunrin naa gbe ikoko ti won fi sun agbari Rofiat si ree ki ọwọ fijilante
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Inu ikoko ti won ti n jo ori rofia ree
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Olori awọn ẹṣọ alaabu ilu, ti a mọ si fifjilante ti wọn kọkọ pe nigba ti oorun gbalẹ ni agbegbe Adatan rèé
Oga ọlopaa Ogun
Àkọlé àwòrán, Oga Olopaa Oyeyemi to ba BBC sọrọ lori ibi ti ọrọ naa de duro bayii ati ohun to ti ṣẹlẹ sẹyin
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Ada , Ọbẹ ati foonu ti wọn ba nibi ti wọn ti ge ori Rofia ree
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Ibi yii ni wọn mu awọn ólopaa lọ pe wọn geb oku Rofia pamọ si lẹyin ti wọn ti ge ori rẹ
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Iyara ti wọn ti pa Rofia ree pẹlu awọn aṣọ ti wọn fi nu ẹjẹ rẹ
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Inu iyara ti wọn ti ba gbogbo nakn naa ree ni Adatan ni Abeokuta
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Beedi ati aṣọ ti awọn to kọkọ wọ inu iyara naa kọkọ ri ree
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Se lootọ ni oogun owo wa?
Iku Rofiat
Àkọlé àwòrán, Awọn ọdọmọkunrin mẹrẹẹrin rèé ti ọwọ ọlọpaa si ti tẹ wọn