Ooni ti Ile-Ife, Pásítọ̀ Sam Adeyemi, Woli Agba, Falz, Mr Macaroni, Tiwa Savage ṣe ṣe àyájọ́ #Endsars!

Oríṣun àwòrán, Others
Awọn eekan lorilẹede Naijiria lori ẹrọ ayelujara lo fi ero wọn han lori ayajọ ifẹhonuhan Endsars to waye lọdun to kọja.
Ọpọlọpọ aworan ni wọn n fi lede lati ṣeranti bi iwọde naa ṣe lọ ni ọdun to kọja.
Wọn fikun un pe awọn ko lee gbagbe lai lai ẹmi to lọ ninu iṣẹlẹ naa.
- 'Fídíò ẹ̀rí táa wò ṣàfihàn ibi tí Baba Ijesha ti ń rán ọmọ Princess létí bí òun ṣe fi ọwọ́ kàn án ní ọmọ ọdún méje'
- Ẹ gbọ́dọ̀ ríi wípé Nnamdi Kanu yọjú sí ilé ẹjọ́ lónìí - Agbẹjọ́rò
- Mọ̀ nípa àwọn ọmọ Naijiria tó fẹ́ kí Ísírẹ́lì tẹ́wọ́ gbà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà Júù
- Wo ohun tí Baba Ijesha sọ fún BBC níbi ìgbẹ́jọ́ rẹ̀
- Wo àwọn gbajúmọ̀ míràn yàtọ̀ sí Tiwa Savage tí fídíò ìbálòpọ̀ wọn ti bọ́ sí orí ayélujára ...
- Wọ́n ní ìpànìyàn wáyé ní Lekki, àmọ́ a kò rí ẹ̀jẹ̀ tàbí òkú èèyàn kankan títí d'òní- Lai Mohammed
- "Free Sunday Igboho" lariwo tó gbóde bí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ ṣe darapọ̀ mọ́ ìwọ́de ENDSARS ní Ibadan
- ''Sójà yìnbọn fún mi ní ìwọdé EndSars lọ́dun tó kọ̀ja, àmọ́ máà tún darapọ̀ mọ́ ìwóde láti ṣèrántí àwọn tó kú''
- EndSARS: Atúpalẹ́ rèé lórí ìkọlù tó wáyé ní Lekki Toll Gate lọ́jọ́ 20 Oct, 2020
- 'Báwo l'èèyèn ṣe lè sín ní London kó di ẹ̀ṣẹ̀ ní Nàìjíríà? Bí ẹ̀sùn ìjọba fún Nnamdi Kanu ṣe rí lójú wa rèé'
Ninu ọrọ tirẹ, Ọọni ti Ile Ife ni ọjọ ayajọ EndSars lorilẹede Naijiria jẹ ọjọ manigbagbẹ ni itan orilẹede Naijiria nitori o jẹ iṣẹlẹ kan patọ to mu ki awọn ọdọ lorilẹede Naijiria parapọ lati ja fun ẹtọ wọn.
Ọọni ni awọn ọdọ naa bẹrẹ fun iṣejọba to dara, ẹtọ araalu to fi mọ ijọba ti ko ni fi ẹtọ araalu dun wọn.

Oríṣun àwòrán, Instagram
Pasitọ Sam Adeyemi ninu arọwa si awọn ọdọ ni ọjọ ayajọ Endsars ni ki awọn ọdọ Naijiria ri ara wọn gẹgẹ bi ọdọ to ni Niajiria ni ọjọ ọla.
Pasitọ Adeyemi ni ki wọn gbaradi fun iṣẹ to wa ninu iwaju wọn, ki wọn si tunbọ ma a pe akiyesi wọn si awọn ohun ti ko ba dara tọ ni ijọbs Naijiria.
O gbadura pe igbiyanju wọn ko ni jasi asan.

Oríṣun àwòrán, Instagram
Bakan naa ni gbajugbaja adẹrinpoṣonu, Woli Agba naa fi fidio lede to sọ wi pe awọn ko ni gbagbẹ gbogbo awọn ti ẹmi wọn sọnu ni ikọlu ti awọn soja ṣe si awọn afẹhonuhan Endsars ni ọdun to kọja.
Wọn kesi si ijọba pe awọn to yẹ ki wọn ma a da abo bo awọn ọdọ ni wọn tun n ṣe ikọlu si wọn.
Gbajugbaja olorin takasufe naa, Tiwa Savage naa fi awo orin sita ti wọn ti n bere ibeere pe tani o fun awọn soja ni aṣẹ lati lọ doju ibọn kọ awọn ọmọ Naijiria ni Lekki Tollgate.
Tiwa Savage ninu orin naa ni awọn ko ni gbagbe lailai nitori awọn ọdọ yii fi ẹmi wọn silẹ lati beere fun ẹtọ wọn.
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post, 1
Bakan naa ni gbajugbaja olorin takasufe, Folarin Falana ti ọpọ eeyan mọ si Falz to fi mọ Mr Macaroni, Charley Boy ni awọn ko ni gbagbe gbogbo awọn to ku ni Lekki Tollgate ti ijọba ko naani wọn.
Bakan naa ni wọn ni ko si nkan ti ijọba le ṣe fun wọn loni ayajọ ọjọ ifẹhonuhan Endsars nitori awọn ko pa eniyan kankan.
Bẹẹ si ni wọn bọ sita ni iye wọn pẹlu ọkọ wọn ti wọn si n tẹ ''horn'' ọkọ wọn.
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post, 2

End of Instagram post, 3

End of Instagram post, 4

End of Instagram post, 5
Awọn ọdọ miran tilẹ kọ orukọ awọn to ba iṣẹlẹ iwọde naa lọ ni ọdun to kọja, ti wọn si n sọ wi pe awọn ko le gbagbe wọn.
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post, 6

End of Instagram post, 7
Amọ titi di asiko yii ijọba ṣi n sọ wi pe ko si ẹni to ku ninu iṣẹlẹ naa, ti awọn soja naa ni awọn ko yin ibọn to le e pa eniyan, wi pe ''Rubber Bullet'' ni wọn yin.