Prince Malik Ado Ibrahim: Wo bí Adama Indimi àti Prince Malik Ado ọmọ Ọba Ohinoyi ilẹ Ebira ṣe fa ayélujára ya

Oríṣun àwòrán, Instagram
Ileeṣẹ BBC ri i ko jọ kaakiri pe Adama Indimi to jẹ ọmọ ọlọrọ to ni ileeṣẹ
"Oil Magnate, Mohammed Indimi ṣẹṣẹ fẹ ọmọkunrin akọkọ Ọba Ohinoyi ti ilẹ Ebira nipinlẹ Kogi, Ọmọwe Ado Ibrahim.
Loju opo Instagtam ni a ti ri oriṣiriṣi fọnran ati fọto ayẹyẹ igbeyawo ọ̀hún
Ayẹyẹ igbeyawo naa bẹrẹ pẹlu aṣalẹ pataki ti wọn n pe ni "Henan night" ni ilu Maiduguri, ipinlẹ Borno lalẹ ọjọ ẹti ọjọ keje oṣu kẹjọ ọdun 2020.

Oríṣun àwòrán, Instagram
Ohun to jẹ kawọn eeyan mii maa pa owe pe olowo n ṣọrẹ olowo ni wipe ẹgbọn Adama Indimi lo fẹ ọmọbinrin aarẹ Muhammadu Buhari, Zarah Buhari.Adama Indimi ti ọpọlọpọ mọ si presido jẹ oniṣowo nla nipa ṣiṣe ara loge.
Wọn yan an ri gẹgẹ bi oludari ikọ to n ko alatilẹyin jọ nigberiko fun iyansipo aarẹ Buhari lọdun 2019.Gẹgẹ bi iroyin ti a tun gbọ, o ti fẹ gbajugbaja olorin Naijiria, DBanj ri.
Baba rẹ, Muhammadu Indimi jẹ oniṣowo ọmọ Naijiria. Oun ni oludasilẹ ati oludari ileeṣẹ Oriental Energy.O ti jẹ ana si aarẹ orilẹede Naijiria nigba kan ri, ajagunfẹyinti Ibrahim Babangida.
Bakan naa, Ọmọwe Ndimi to jẹ ọkan lara awọn biliọniaa to lowo ju ni Naijiria jẹ ana si aarẹ Muhammadu Buhari lọwọlọ ati ana minisita tẹlẹri lasiko ijọba Abacha, Bashir Dalhatu.
Ọmọ rẹ ọkunrin to jẹ ẹgbọn Indimi lo fẹ ọmọbinrin aarẹ Buhari, Zarah.

Oríṣun àwòrán, Instagram
Ni ti Arẹmọ Malik Ado Ibrahim to jẹ ọmọ Ọba Ohinoyi ti ilẹ Ebira, wọ bi i ni Naijiria ṣugbọn ilu UK ati US lo ti lọ kawe.Ọkọ ni oludari agba ati alaga ileeṣẹ Nigus Enfinity to jẹ ileeṣẹ kan to dowo pọ pẹlu BYD ti China.
Bakan naa arẹmọ yii ni ifẹẹ ọkọ pupọ to si ti n ṣe katakara ọkọ lati ọdun 1990. Koda o fẹran ko maa da nikan fi ọkọ sare ije.
O n ṣiṣẹ pẹlu ileeṣẹ Proton and Lotus to si ṣe ipo Lotus fun ijọba Malaysia lọdun 1999. Oun ni ọmọ adulawọ akọkọ to ṣiṣẹ pẹlu ileeṣẹ Formula 1.

Oríṣun àwòrán, Instagram
Lẹyin ti wọn ti ṣe igbeyawo Nikkah nilana ibilẹ, Adama ati Malik ni awọn yoo mu ọjọ mii lọtọ fun igbeyawo nilanaa tawọn oyinbo alawọ funfun.
Wo àwọn fọ́ran to jẹyọ nibi ayẹyẹ náà
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post, 1

End of Instagram post, 2

End of Instagram post, 3

End of Instagram post, 4

End of Instagram post, 5

End of Instagram post, 6