Coronavirus in Nigeria: Ǹjẹ àgbo lè ṣe òògùn coronavirus?

Àkọlé fídíò, Ǹjẹ àgbo lè ṣe òògùn coronavirus?

Oriṣiiriṣii nnkan lawọn eeyan n sọ pe o le wo aarun coronavirus ti o ba gbogbo aye finra lọwọ.

Laipẹ yii ni aarẹ orilẹede Madagascar polowo agbo kan pe o le wo aarun aarun coronavirus.

Ko si ohun to jọ bẹẹ raa! Ajọ eto ilera lagbaye, WHO sọ pe iwadii si n lọ lọwọ lori ati wa oogun tabi abẹrẹ to le wo coronovirus ṣugbọn ko sii oogun rẹ bayii.

Alaye lẹkunrẹrẹ fidio yii.