Coronavirus in Nigeria: Ǹjẹ́ òògùn vitamin C lè pa coronavirus?
Iroyin ti lu ori ayelujara pe wi pe lilo oogun vitamin C la pa aarun coronavirus to n ba gbogbo agbaye finra lọwọ yii.
Amọ ajọ eleto ilera lagbaaye, WHO ti ṣalaye pe ko si ohun to jẹ bẹẹ rara.
Ajọ WHO ni titakete si ara ẹni lo ṣe pataki bayii lati dena aarun covid-19.
BBC Yoruba ṣe alaye lẹkunrẹrẹ lori ọna lati le dena aarun covid-19 lai lo oogun vitamin C.
- Bí mo ṣe ṣẹ́gun Coronavirus rèé - Seyi Makinde
- Coronavirus: Ọmọ márùn ún ni mo ní, ṣùgbọ́n kò sí oúnjẹ fún wa lásìkò ìgbélé yìí -Olùgbé ìlú Eko
- Èèyàn mẹ́fà míràn tún ti ní àrùn Coronavirus ní Naijiria
- Kí ló mú àwọn aládùúgbò Mọ́ṣáláṣí Alhaja kọlu àwọn ọlọ́ọpàá?
- Èyí ni ìdí tí coronavirus ṣe n pa àwọn kan, tí kò sì pa àwọn kan
- Coronavirus- Atọ́nà bí nkàn ṣe ń lọ ní Afirika