Coronavirus and Kayeefi: Òtítọ́ àti irọ́ wo ló wà nípa oògun owó àtàwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kàyééfì míràn
Ibi gbogbo la n dana alẹ ọbẹ kan n gbe ibi kan dun ju ibi kan lọ ni.
eyi lo tun difa fun akanṣe akojọpọ iroyin Kayeefi BBC News Yoruba tọtẹ yii eyi to kaakiri lati ilu Ibadan de ipinlẹ̀ Cross river, Iwo ni ipinlẹ Ọṣun.
Ẹ gba a kẹ tọọ wo, oyin mọmọ!
- Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ṣetán láti dán abẹ́rẹ́ covid-19 tí fásítì Oxford ṣe wò nílẹ̀ Afirika
- Kòkòrò coronavirus sì wà lára mi títí mo fi kúrò ní ibùdó ìtójú àwọn alárùn covid-19 l'Eko- Motosinoluwa Afolaranmi
- Mo wọ bàtà àti fìlà wọ pẹpẹ Cele láti ṣe wáàsí, kò sí ṣọ́ọ̀ṣì tí n kò le wọ̀ - Sheik Buhari ọmọ Musa
- Gómìnà Ondo Akeredolu ṣí ilẹ̀kùn ṣọ́ọ̀ṣì àti mọ́ṣáláṣí sílẹ̀ fún ìjọ́sìn
- Ìtàn ìgbésí ayé Oshodi, ọmọ Tápà léǹpe tó di akọni ní ìlú Eko
- Femi Adebayo di àgbà àáfà òníláwàní, Iyabo Ojo fi sìgá dárà, Allwell Ademola di ọmọdé padà, tí Wazo si bímọ tuntun