Samuel ni ìdàgbàsókè Nàìjíríà ló jẹ òun lógún!
Aworan nkan to ba n ṣẹlẹ lasiko ti mo fẹ ya aworan ni mo n ya- Samuel.
Odọmọde ayaworan pẹlu gege awọn ọmọde (Pencil), Samuel Ogooluwa Esan ni BBC ba lalejo.
Odọmọde yii maa n ya aworan oriṣiriṣi nipa nkan loriṣiriṣi fun awọn eniyan ni.
Samuel ṣalaye pe awọn nkan to ba n ṣẹlẹ ni ayika oun ati agbegbe oun lo maa n jẹ atọna fun oun lori aworan to yẹ ni yiya.
- Atipo Naijiria 50 rigbala lori omi
- #BBCGOVDEBATE: Ọgbọ́n ìmọ̀ àti òye ní ń ò fi ṣe ìjọba- GNI
- 'Ọọ̀nì ńlá méjì ní wọ́n jọ ń gbé nínú iyàrá'
- Fasiti Ọbafẹmi Awolowo University pariwo síta pé àwọn èèyàn ilé ifẹ̀ kan da májèlé sómi iléèwé
- Afárá odo ọya keji :Ta ni yóò parí rẹ?
- Èèwọ̀ ni láti pa ẹja nínú odò Sogidi ni Aáwẹ́ nipinlẹ Oyo
Ogooluwa ni awọn aworan naa ni oun n ya lati jẹ ki awọn eniyan mọ nkan ti oun ni lọkan ni asiko kọọkan.
Ati pe aworan yiya kii jẹ ki awọn eniyan le gbagbe iṣẹlẹ to ṣẹlẹ nigba kan ri.
- Iṣẹ́ ti bẹ̀rẹ̀ lórí àfikún owó oṣù tuntun- Keyamo
- Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò Patrick Day dèrò ọ̀run lẹ́yìn tó gba ẹ̀ṣẹ́ s'órí!
- Ìná ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ NLC ati ìjọba kò wọ̀ níbi ìpadé
- Ọmọ Nàìjíríà, ẹ forijìn mí! Aisha Buhari tọrọ ìdáríjì lórí fídìo tó jáde
- Àwọn ojú oge Yollywood t'ọ́jà wọ́n ṣì ń tà wàràwàrà
- Àgbo ló ṣiṣẹ́ fún mi l''asìkò tí mò ń wojú Olúwa fún ọmọ - Toyin Abraham