Caster Semenya: kíní ìdájó yìí dà fún obìnrin àti eré ìdáraya

Bí ọmọbinrin South Africa Caster Semenya to ń sáré ṣe fìdírẹmi lóri ẹsùn ìdẹ́yẹsini tó fi kan IAAF níle ẹjọ, BCC ń wo ohun to túmọ si fún àwọn obinrin àti eré ìdáraya.
Ọmọbinrin South Africa tó ń sare ori pápá Caster Semenya ti kúna ló ẹsún to fi kan ajọ to n moju to ere ori pápá lágbàye International Association of Athletics Federation (IAAF) to sọ pe kò tọnà láti máa jẹ ki èní to ni okún jú àwọn akẹgbẹ rẹ lọ, tí wọn pè ni (testosterone) láti mú àdíku báà nítori pé ìdẹ́yẹsi ni ni.
Ẹni ọmọ ọdun méjìdínlogun ti fẹsùn kan IAAF lóri ìpínnu rẹ̀ láti mú àdínku ba okún nínú àwọn obinrin to n sáre fún eré ijé to bá ti jú irínwo mítà lọ.

Oríṣun àwòrán, Reuters
Semenya, tó ti jáwe olubori nígbà mọ́kàndínlọgbọ̀n nínú eré ije oni mítà ọgọjọ nítori pé a bíi gẹ́gẹ́ bi ẹni to ni ìṣẹ̀dá okùnrin, wọn sába máa n ni abùdá àdámọ ọkùnrin pàápàá ninu okùn.
Idájọ ti wọn da túmọ si pe Semenya yóò maa lo oogun ti yóò maa mú àdínku bá okún náà nígbà ti wọn ba fẹ sá eréje to kéré si àwọn eyi ti wọn là sílẹ.
Three sports judges in Switzerland have taken more than two months to reach this verdict - indicating the sensitivity and complexity of the case.
Awọn àdájọ eré ìdáraya métà ní Switzerland lo odidi oṣù meji láti gbé ìdájọ wọn jáde èyí to ṣe afihan bi ìdájọ náà se se pàtàkì tó.








