Ahmed Musa padanu ìyá rẹ̀ lẹyin aisan ranpẹ Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa dabira Nàìjírìa nínú ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé lorílẹ́èdè Russia 24 Sẹ́rẹ́ 2019 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 25 Sẹ́rẹ́ 2019
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Agbabọọlu ọmọ Naijiria Ahmed Musa ti padanu iya rẹ bayi.
O fi iroyin naa to awọn ọmọ Naijiria leti lori Twitter ni Ọjọbọ niga to ni "Ọjọ ibanuje ni ọjọ yii jẹ fun aye mi. Mo ti padanu iya mi."
Skip X post Allow X content? This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
Accept and continue Warning: Third party content may contain adverts Content is not available
View content on X BBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Exclusive: Tí a bá gbé ẹ̀ṣẹ̀ àwọn tó ń ṣèjọba lọ́wọ́ jáde, wọn yóò wọná - Obasanjo", Duration 9,25 09:25 Àkọlé fídíò, Obasanjo: Atiku kìí se Áńgẹ́lì, àmọ́ yóò se dáadáa ní ìlọ́po méjì ju Buhari lọ O ti sọ tẹlẹ pe iya oun ṣaarẹ ko to di pe o ku.
Oríṣun àwòrán, @ahmedMusa718
Àkọlé àwòrán, iya ni wura iyebiye Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "BBC Yoruba ń pè yín sí ìpàdé ìtagbangba", Duration 0,51 00:51 Àkọlé fídíò, ìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko. Ni ana ni o fi aworan iya rẹ sori Twitter ninu eyi to fi n ki pe ki o dara le.
Oríṣun àwòrán, @Ahmedmusa718
Àkọlé àwòrán, abiyamọ ni gbogbo aye n gbadura ko duro jẹun ọmọ
Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Day 24: Ǹjẹ́ O lè dìbò fún ẹni tí àlùfáà tàbí ìmámù rẹ́ bá yàn?#BBCNigeria2019", Duration 3,51 03:51 Àkọlé fídíò, 2019 Elections: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Play video, "Wọ́n fi iṣẹ́ tàn ań wá sí Eko, kí wọ́n tó fun ní HIV", Duration 5,12 05:12 Àkọlé fídíò, Ọ̀tọ̀ ni nkan tí wọ́n sọ fún ẹbí rẹ̀, iṣẹ́ aṣẹ́wó ni wọ́n fi n ṣe