Àjàgbé Toriola Oyewo: Ọdún 1999 ni mo tí ń gbìyànjú láti gba SAN kí wọ́n tó fún mí ẹ̀ní ọdún 90
Amofin Agba, Ajagbe Toriola Oyewo ni itan aye rẹ ṣe apejuwe bi eniyan ko ṣe gbọdọ ro ara rẹ pin ti nkan ko ba lọ bi o ṣe yẹ ko lọ.
Ajagbe Toriola di agba Amofin SAN ni ẹni aadọrun ọdun lẹyin gbogbo igbiyanju rẹ lati bi ogun ọdun mejilelogun ṣẹyin.
- À ń wá gbajúmọ̀ apanilẹ́ẹ̀rín, Cute Abiola o! A kò gbúrò rẹ̀ nílé - Mọ̀lẹ́bí
- Ìjọba ìpínlẹ̀ kàn kéde ọ̀jọ ìsinmi ní ìrántí Zik, wo òhun tí wọ́n yóò máa ṣe lọ́jọ́ ìbí rẹ̀
- Amerika sọ̀rọ̀ sókè lórí àbájáde ìwádìí #EndSARS, Ó ní ìjọba gbọ́dọ̀ tètè wá nǹkan ṣe
- Super Eagles rápálá wọ ìpele kómẹsẹ̀-ó-yọ Qatar 2022, ọ̀mì ni wọ́n ta pẹ̀lú Cape Verde
- Èèmọ̀! Ọmọbìnrin kan bá ara èèyàn nínú fìríìjì ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀
- 'Ọ́lọ́run mo dúpẹ́ o pé wọn ò kà mí mọ́ ẹni tó ti wọlẹ̀ báyìí níbi afẹ́fẹ́ gáàsì tó búgbàmù'
Baba Oyewo ni ọdun 1999 ni ohun ti n tiraka lati gba SAN, ọkan lara awọn to gba oye SAN mọ lọwọ ni Gani Fawehinmi ni ọdun 2001.
Ẹkunrere fidio naa sọ iriri rẹ laye ati bi o ṣe laaja.