Mckinley Erves di ẹni tó ń ríran rí àwọ̀ nípasẹ̀ ìrànlọ́wọ́ àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀

Àkọlé fídíò, Mckinley Erves di ẹni tọ ń ríran rí aàwọ̀ nípasẹ̀ ìrànlọ́wọ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀

Ko si ohun ti Olorun ko le yi pada!

Mckinley Erves jẹ ọdọmọkunrin ti kii riran ri awọ paapaa aawọ bii pupa ati awọn miran to n tan.

Lati kekere lo ti ni ipenija iju yii ni eyi ti inu rẹ ko dun sii.

Lọjọ kan ni awọn ọrẹ rẹ yaa lẹnu nipa ṣiṣe gilaasi oju kan fun un ni eyi to mu inu rẹ dun.

Gilaasi oju yii lo fi n riran ri awọ ni ayika rẹ.

Wo bi inu rẹ ṣe dun to nigba akọkọ to kọkọ riran ri awọ lara ọkọ a i ni ayika rẹ...