World Aids Day: Wo bí kòkòrò ààrùn HIV se bẹ̀rẹ̀ lágbàyé!
Ọjọ Kini, Osu Kejila, ọdọọdun ni Ajọ Agbaye fi silẹ lati maa fi se ayajọ ọjọ kokoro aarun HIV to lee sekupani.
Fidio yii se afihan bi Dokita lati orilẹede Amerika se kọkọ se awari kokoro HIV lẹyin to sekupa eniyan kan.

- Ugbochukwu Michael: Ààrùn kòkòrò HIV kìí ṣe ìdájọ ikú
- Olorì Aláàfín tẹ́lẹ̀, Anuoluwapo Adeyemi gba àmì ẹ̀yẹ lórí ipa tó kó nínú oge ṣíṣe
- Gbajugbaja òṣèré ''Toromagbe'' nínú fíìmù ''Arelu'' ti jáde láyé
- Ṣé àwọn ìjayà ajaguntà ilẹ̀ òkèrè leè bá Nàìjíríà fòpin sí ìṣòro àbò?
- Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?
Ayajọ ọjọ yii wa fun pipe akiyesi awọn eniyan si awọn ohun to le fa aarun naa, ati itọju to peye to wa lati tọju wọn.
Iwadii fihan pe eniyan miliọnu marundinlọgọrin lo ti ni aarun kokoro naa.