Àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé òbí wọn máa ń padà wá sáyé
Yewande, Yetunde, Yejide, Iyabọ: awọn orukọ to mu itan da ni!
Ile la n wo ni ilẹ Yoruba ki a to sọ ọmọ lorukọ!
- Coronavirus: Gómìnà Wike ìpínlẹ̀ Rivers wó ilé ìtura méjì lulẹ̀ torí wọ́n tàpá s'ófin kóńlé-ó-gbélé
- Àwọn nǹkan tí obìnrin lè ṣe pẹ̀lú olólùfẹ́ oníwà ipá lásìkò ìgbélé Coronavirus yìí
- Coronavirus: Ǹjẹ́ àwọn dókítà tó ń tọ́jú eyín ń ṣisẹ́ lásìkò pàjáwìrì? Àti àwọn ìbéèrè míràn
- Coronavirus: Kíni àwọn àmì tuntun tó n fihàn?
Iran Yoruba kii sọ ọmọ ni orukọ lai kọkọ wo nkan to n ṣẹlẹ ninu aye wọn, ninu ẹbi wọn ati ninu agboole wọn ki wọn to sọ ọmọ tuntun lorukọ.
Loni BBC Yoruba lọ wadii iru ọmọ ti Yoruba n pe ni Yetunde lẹyin ti a bii.
- Ramil, omọ ogun ilẹ̀ ní Russia yìnbọn pa akẹgbẹ́ rẹ̀ mẹ́jọ!
- Buhari kàn ń kọwọ́ bọ̀wé nílẹ̀ òkèèrè kiri ni, a ò rí ipa ní Nàijíríà- Onímọ̀ ọrọ̀-ajé
- Tọwọ́ tẹsẹ̀ laá fi gba ìrànwọ́ owó ẹ̀kọ́ Almajiri ní ìpinlẹ̀ Oyo- Alága Subeb
- Ìbẹ̀rẹ̀ mi kò rọrùn rárá, omi máa ń bọ́ lójú mi tí mo bá rántí àkókò náà - Small Doctor
Yewande, Yetunde, Yejide, Iyabọ jé awọn orukọ ti a n sọ ọmọbinrin ti a bi lẹyin iku iya baba rẹ tabi ti iya iya rẹ.
Ti ọmọ naa ba jẹ ọmọ okunrin, Babajide, Babatunde, Babawale, Babarinde ni wọn n sọ ọ.