You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
World Cup 2022 - Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìdíjé Ife Agbaye
Ọgunjọ, Osu Kọkanla ni ife ẹyẹ agbaye, Qatar 2022 yoo bẹrẹ ni ọjọ kejidinlogun, oṣu kejila, ni ọdun 2022.
Igba kejilelogun ti idije yii yoo ma waye niyii.
Eleyii si jẹ igba akọkọ ti wọn yoo gba bọọlu naa ni orilẹede Arabu.
BBC ṣe akojọpọ bi ifẹṣẹwọnṣẹ yoo ṣe lọ ati esi ifẹwọnsẹ ni idije Ife Ẹyẹ agbaye Qatar, 2022.