You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Femi Adebayo, Mercy Aigbe, fíìmù Lisabi, àti àwọn míì tó borí níbi àmì ẹ̀yẹ 2025 AMVCA
Orisirisi ara lo waye nibi ami ẹyẹ African Magic Video Choice Awards ti ọdun 2025.
Bi aṣọ ṣe n pe aṣọ ran niṣẹ, ni awọn irun ati awọn nnkan iṣaraloge naa ko gbẹhin laarin awọn olukuluku eeyan to kopa nibi eto naa to waye lọjọ Abamẹta, ọjọ kẹwaa oṣu Karun-un.
Ami ẹyẹ naa ni wọn fi n mọ riri awọn oṣere, olukọtan, adari ere, ati awọn iṣẹ miran ni ẹ̀ka amuludun fiimu ati sinima, nilẹ Africa.
Ni AMVCA ti ọdun yii, ipele ami ẹyẹ mẹtadinlọgbọn lo waye - awọn oluworan ere ati ololufẹ sinima dibo ni ipele mẹsan-an, ko si idibo fun ipele méjìdínlógún.
Fun awọn ipele ti ko ni idibo ninu, igbimọ awọn adajọ ti AMVCA yan, lo mojuto o. Ogbontarigi onisinima, Femi Odugbemi lo lewaju awọn adajọ ọhun.
Fiimu ti Femi Adebayo gbe jade, Seven Doors, ni wọn fi orukọ rẹ silẹ fun ami ẹyẹ to pọ julọ - ami ẹyẹ mọkanla.
Lisabi (The Uprising) fiimu Lateef ati Bimpe Adedimeji, lo wa ni ipo keji gẹgẹ bi fiimu ti wọn fi orukọ rẹ silẹ julọ - ami ẹyẹ mẹwaa ni tiẹ.
Awọn ti wọn fi orukọ wọn silẹ fun ami ẹyẹ, ati awọn to ja mọ ni AMVCA 2025
Best Movie
- Lisabi: The Uprising
- Skeleton Coast
- Suspicion
- Inkabi
- House Of Ga'a
- Freedom Way - Olubori
- Christmas In Lagos
- Farmer's Bride
Best Lead Actor
- Gideon Okeke (Tokunbo)
- Bucci Franklin (The Weekend)
- Femi Branch (House of Ga'a)
- Thapelo Makoena (Skeleton Coast)
- Bimbo Manuel (Princess On A Hill)
- Stan Nze (Suspicion)
- Femi Adebayo (Seven Doors) - Olubori
- Adedimeji Lateef (Lisabi - The Uprising)
Best Lead Actress
- Chioma Chukwuka (Seven Doors) - Olubori
- Gbubemi Ejeye (Farmer's Bride)
- Uzoamaka Onuoha (Agemo)
- Uche Montana (Thinline)
- Uzoamaka Aniunoh (Phoenix Fury)
- Hilda Dokubo (The Uprising: Wives On Strike 3)
- Bimbo Ademoye (Anikulapo: Rise Of The Spectre)
Best Supporting Actress
- Meg Otanwa – Inside Life
- Tina Mba – Suspicion
- Ireti Doyle – All's Fair in Love
- Ini Dima-Okojie – Skeleton Coast
- Mercy Aigbe – Farmer's Bride - Olubori
- Omoni Oboli – The Uprising: Wives on Strike 3
- Darasimi Nnadi – Aburo
Best Supporting Actor
- Gabriel Afolayan – Inside Life - Olubori
- Adedayo Adebowale Macaroni – Lisabi: The Uprising
- Aliu Gafar – Seven Doors
- Femi Jacobs – Freedom Way
- Richard Mofe-Damijo – Christmas In Lagos
- Uzor Arukwe – Suspicion
- Mike Afolarin – House of Ga'a
- Efa Iwara – Princess on a Hill
Best Director
- House of Gaa
- Inkabi
- Seven Doors
- Skeleton Coast
- The Man Died - Olubori
- The Weekend
Best Cinematography
- Agemo
- Inkabi
- Lisabi (The Uprising)
- Skeleton Coast
- Soft Love
- The Legend of The Vagabond Queen Of Lagos - Olubori
- Yen Ara Asaase Ni
Best Editing
- Inkabi (Tongai Furusa) - Olubori
- Christmas in Lagos (Martini Akande)
- Skeleton Coast (Jordan Koen)
- Soft Love (Holmes Awa, Paballo Modingoane)
- Lisabi: The Uprising (Anthill Studios)
- Princess on a Hill (Laughter Ephraim, Peter Ugbede)
Best Costume Design
- Aníkúlápó (The Rise of the Scepter)
- Christmas in Lagos - Olubori
- House of Gaa
- Lisabi
Best Makeup
- Aníkúlápó (The Rise of the Scepter)
- Inside Life
- Farmer's Bride
- Lisabi (The Uprising) - Olubori
- Seven Doors
- Suspicion
Best Digital Content Creator
- Iyo Prosper Adokiye - Olubori
- Maryam Apakagi-Greene
- Elozonam Ogbolu, Hoviare Freedom, Chiamaka Uzokwe
- Jide Pounds Ibitoye
- Ariyiikedimples, Brain Jotter
Best Documentary
- Mai DùnDún - Olubori
- I Will Remember You
- On Your Own
- Walvis Tale
Best Series Scripted
- Cheta M
- Inside Life - Clarence Peters (Olubori)
- Princess on a Hill
- Roses & Ivy
- Seven Doors
Best Series Unscripted
- Ebuka Turns Up Africa
- Skillers: The Building Reality Show
- Style Magnate
- Take Me Home
- Wa Milele - Olubori
Best Writing - Movie
- A Ghetto Story
- Christmas in Lagos
- Freedom Way - Olubori
- House of Gaa
- Skeleton Coast
- The Weekend
Best Writing - TV Series
- Aníkúlápó (Rise of the Spectre)
- Cheta M
- Princess on a Hill
- Roses & Ivy
- Seven Doors
- Untying Kanti - Olubori
Best Art Direction
- Aníkúlápó (Rise of the Spectre)
- Christmas in Lagos
- Farmer's Bride
- Lisabi (The Uprising) - Olubori
- Seven Doors
- The Man Died
Best Sound Design
- Beast of Two Worlds
- Freedom Way
- Inkabi
- Lisabi (The Uprising)
- Seven Doors
- Suspicion - Olubori
Best Music/Score
- Freedom Way
- Inkabi
- Seven Doors - Olubori
- Skeleton Coast
- Soft Love
Best Short Film
- Brukaci - Olubori
- Sukari
- The Incredible Sensational Fiancée of Seyi Ajayi
- What Are You Truly Afraid Of?
Best Unscripted M-Net Original
- Husband Material
- Nigerian Idol (Season 9) - Olubori
- Overall Best
- Pastor Wants a Wife
Industry Merit Award
Nkem Owoh and Sani Mu'Azu - Awọn olubori
Trailblazer Award
Kayode Kasumu - Olubori
Best Indigenous Language (West Africa)
- Seven Doors
- Lisabi: The Uprising - Olubori
- Kaka
- Anikulapo: The Rise of the Spectre
- Mai Martaba
Best Indigenous Language (East Africa)
- The Caller
- Empty Grave
- Makosa ni Yangu - Olubori
- Sabotage
- Wa Milele (Forever?)
Best Indigenous Language (South Africa)
- Walvis Tale
- The Vow
- Mwizukanji - Olubori
- Man of Gold
- Lukas
Best Indigenous M-Net Original
- Mai Shayi
- The Caller
- Show Me The Way
- Ebighi Ebi
- Subterranea
- Onye Agbata Obim
- Amoanimaa's Era
- Z im Uzo - Olubori
Best Scripted M-Net Original
- Uriri
- All Mine
- My Fairytale Wedding - Olubori
- Italo
- The Caller
- Kam U Stay
Best MultiChoice Talent Factory
- Gone (West Africa)
- Everything Light Touches (West Africa) - Olubori
- The Immersive Alarm (East Africa)
- Deadbeat (East Africa)
- Mwananga (Southern Africa)
- Rivals in Time (Southern Africa)