Ṣé bí adẹrìn-ínpòṣónú Layi Wasabi ṣe mú lẹ́nu ló láyà tó?
Ṣé bí adẹrìn-ínpòṣónú Layi Wasabi ṣe mú lẹ́nu ló láyà tó?

Oríṣun àwòrán, BBC/layi Wasabi
Lára àwọn adẹ́rìn-ín-pòṣònú tó ń mi orí ayélujára tìtì lásìkò yìí ni Isaac Layiwola tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Layi Wasabi.
Ohun tí Layi Wasabi gbajúmọ̀ fún ni ṣíṣe bíi agbẹjọ́rò nínú àwọn eré tó máa ń ṣe.
Layi Wasabi darapọ̀ mọ́ BBC News Yorùbá lórí ètò 'Só o láyà' tọ̀tẹ̀ yìí lati mọ̀ bí Yorùbá rẹ̀ ṣe dáńtọ́ tó.
Ẹ wó fídíò òkè yìí kí ẹ fún Layi Wasabi ní máàkì.





