Ẹni tí kò bá rí tó N1m lọ̀dún kò níì san owó orí àti àwọn àlàyé mìí nípa àbá òfin owó orí tuntun

Àkọlé fídíò,
Ẹni tí kò bá rí tó N1m lọ̀dún kò níì san owó orí àti àwọn àlàyé mìí nípa àbá òfin owó orí tuntun
    • Author, Busayo James-Olufade
    • Role, Senior Journalist

Lati ọsẹ diẹ sẹyin ni oriṣiriṣi ariyanjiyan ti n waye lori ipa ti aba ofin owo ori tuntun ti Aarẹ Bola Tinubu gbe lọ sile aṣofin.

Bi awọn kan ṣe n sọ pe ofin naa to ba di bibuwọlu yoo fa ifasẹyin ba awọn ẹkun kan, ni awọn miran n sọ pe ofin naa gan-an ni Naijiria nilo lasiko yii.

Awọn miran ni ti wọn n gboriyin fun Aarẹ Tinubu pe, iṣẹ takuntakun lo ṣe nipasẹ igbimọ to ṣe atunsẹ ofin owo ori ti Naijiria n lo lati ọpọlọpọ ọdun.

Ninu fidio yii lẹ o ti ri idahun si gbogbo ibeere ti ẹ ba ni lori ọrọ ofin owo ori tuntun ti ijọba fẹ ẹ ma a ṣe amulo.