Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Gomina Seyi Makinde ti buwọ́lu ₦4.08b fẹbi awọn eeyan to pàdánù ẹ̀mí wọn àti dúkìá nínú ìbúgbàmù Bodija n'Ibadan
Agbenusọ awọn eeyan naa, Muyiwa Bamgbose, lo fidi ọrọ yii mulẹ.
O ni awọn ti ile wọn wa ni ẹẹdẹgbẹta mita yika ibi ibugbamu naa nikan ni iranwọ yii wa fun.
Ọjọ kẹrindinlogun, oṣu Kinni, ọdun 2024 ni ibugbamu ọhun ṣẹlẹ.
Eeyan maarun lo ku, ti ọpọ dukia si ṣofo nibi iṣẹlẹ naa
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Afurasí ọdaran kan ti kú sí àhámọ́ ọlọpaa lẹ́yìn tí wọ́n mú u fun ohun tó kọ s'ójú opo ayelujara X rẹ.
Albert Ojwang, ọmọ ilẹ Kenya ni awọn ọlọpaa mu pe o kọ ohun ti ki i ṣe ododo sori ayelujara.
Ki lo wa ṣeku pa a?
Alaye wa lori ikanni BBC YORUBA
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ojude Ọba 2025 migboro titi n'Ijebu Ode.
Bẹẹ ni, amọ ki lo de ti Kabiyesi Awujale Ilẹ Ijebu, Ọba Sikiru Adetona ko fi si nibẹ?
Ko ṣẹlẹ ri ni toootọ, amọ, awọn to sun mọ Kabiyes ti ṣalaye ohun to fa a
Ti ẹ ba fẹ mọ idi abajọ…

