Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ẹlẹrii kan lori igbẹjọ gomina banki apapọ Naijiria, CBN, tẹlẹ ri, Godwin Emefiele ti sọ fun ile ẹjọ pe
ko si akọsilẹ fun ẹgbẹrun lọna irinwo owo dọla toun gbe fun un lasiko to wa nipo gomina banki CBN
Ki ni Emefiele wa sọ sọrọ naa?
Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Njẹ o ti gbọ àrùn nipa Diphtheria tó pa ọmọdé méje, tí ọ̀pọ̀ sì wà nílé ìwòsàn?
Ki ni tuntun nipa arun naa? bunmi gbọ
Awọn dokita onimọ Iṣegun ni arun diphtheria jẹ oriṣi kokoro aifojuri 'bacteria' to ma n kọlu eroja to n daabo bo imú ati ọ̀fun
Lootọ ni oogun oyinbo ma n wo diphtheria, ṣugbọn..
Ṣugbọn ki ni?
Lọ ka iyoku lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ariwo sọ lórí bí sọ́jà obìnrin ti dero atimọle lori ẹ́sùn pé ó jí owó ìyàwó ọ̀gá rẹ̀ gbe
Iroyin fidi rẹ mulẹ pe soja ọhun ti wa ahamọ bayii fun ọsẹ mẹfa
Alukoro ileeṣẹ ọmogun ti salaye pe ''bi Maidoki ṣe wa ni atimọle ko lodi sofin ninu iṣẹ ologun
Fun ẹkunrẹrẹ…
















