Ṣó o Láyà: Tunde Kelani kópa nínú ìdánwò tó dá lórí àṣà àti èdè Yorùbá

Àkọlé fídíò, Ṣó o Láyà: Tunde Kilani kópa nínú ìdánwò tó dá lórí àṣà àti èdè Yorùbá
Ṣó o Láyà: Tunde Kelani kópa nínú ìdánwò tó dá lórí àṣà àti èdè Yorùbá

Odu ni Tunde Kelani ninu ka fi ede Yoruba dara tabi ka fi ede Yoruba powe ati ka se sinima to sọ nipa aṣa wa.

A beere awọn ibeere to ni ṣe pẹlu ede Yoruba lọwọ rẹ, gẹgẹbi ẹni to n gbe aṣa ati ede Yoruba ga ninu awọn sinima rẹ.

Ka ma parọ, Tunde Kelani gbiyanju pupọ. Ẹyin gan ẹ funra maa ri ninu fọnran yii.

Nibẹ lo ti dahun awọn ibeere lọkan o jọkan eyi to nii ṣe pẹlu ede Yoruba, aṣa ati iṣe wa.

Tunde Kelani