Ìṣípòpadà bá àwọn Kọmíṣọ́nà àti AIG ogójì ní Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Nàìjíríà

Aworan ọga agba ajọ ọlọpaa, Kayode Egbetokun

Oríṣun àwòrán, Facebook/Kayode Egbetokun

Ọga agba ajọ ọlọpaa nilẹ Naijiria, Olukayode Egbetokun, lo ti paṣẹ iṣipopada fawọn lọgalọga ogoji lajọ naa.

Awọn lọgalọga naa lo jẹ igbakeji ọga agba (AIG) mẹrinla ati kọmiṣọna mẹrindinlọgbọn ti wọn fọnka sawọn oriko ajọ naa kaakiri Naijiria.

Agbẹnusọ ajọ ọlọpaa ni Naijiria, Olumuyiwa Adejobi, ninu atẹjade to fi lede wi pe iṣipopada yii lo waye lati le jẹ ajọ naa lee ṣe iṣẹ rẹ bo ṣe tọ, ni ibamu pẹlu ofin, ati lati lee tẹsiwaju bii ọrẹ araalu.

Adejọbi to wi pe lẹyẹ o sọka ni ki awọn tọrọ naa kan o lọọ wọṣẹ laaye tuntun ti wọn fi wọn si fi kun pe ọga agba ajọ ọlọpaa nilẹ yii rọ awọn lọgalọga naa lati ṣe iṣẹ wọn ni ibamu pẹlu ipinnu ijọba lati mu agbega ba ọrọ-aje ilẹ yii ati lati mu idagbasoke ba Naijiria.

O wipe Egbetokun ṣe atẹnumọ idi pataki ti wọn fi gbọdọ jẹ ki awọn to ba wa labẹ wọn o mu iṣẹ ni ọkunkundun ki wọn si ṣee bii ojulowo akọṣẹmọṣẹ ọlọpaa.

Bakan naa lo rọ wọn lati fọwọsowọpọ pẹlu gbogbo awọn alẹnulọrọ lagbegbe wọn ki iṣẹ wọn o lee rọrun sii.

Àwọn wo gan ni ìṣípòpadà náà bá, ààyè wo ni wọ́n sì gbé wọn lọ?

AIG:

i. Zone 7 Abuja – AIG Ogundele Joshua Ayodeji

Skip podcast promotion and continue reading
Èyí ni ìkànnì Whatsapp wa

Àjáàbalẹ̀ ìròyìn BBC News Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa nibì

End of podcast promotion

ii. Zone 11 Osogbo – AIG Patrick Ogon Edung

iii. Border Patrol FHQ – AIG Badru Banji Lawal, mni

iv. Zone 8 Lokoja – AIG Bartholomew N. Onyeka

v. DOPS FHQ – AIG Suleiman A. Yusuf, mni

vi. FCID Annex Alagbon Lagos – AIG Idowu Owohunwa

vii. Maritime Lagos – AIG Rhoda Adetutu Olofu

viii. Zone 13 Ukpo Dunukofia Awka – AIG Godwin N. Aghaulor

ix. ONSA Abuja – AIG Effiom Emmanuel Ekot

x. CTU FHQ Abuja – AIG Anene Ndu Innocent

xi. Zone 16 Yenagoa – AIG Odama Paul Ojeka

xii. Zone 4 Makurdi – AIG Ebong E. Eyibio, mni

xiii. Zone 17 Akure - AIG Adebowale Williams

xiv. Investment FHQ Abuja - AIG Sahabo A. Yahaya, mni

Kọmiṣọna:

i. Benue State - CP George Chijioke Chuku

ii. Jigawa State - CP Ahmed Abdullahi Tijani

iii. Niger State - CP Dan Mamman E. Shawulu, fsi

iv. Gombe State - CP Usman Hayatu

v. Imo State - CP Danjuma Aboki

vi. Rivers State - CP Disu Olatunji Rilwan

vii. Taraba State - CP Joseph Eribo

viii. Osun State - CP Isyaku Mohammed

ix. Safer Highways FHQ - CP Mohammed Barde

x. PPP DLS FHQ - CP Polycarp Nwonyi Emeka

xi. Anti-Human Trafficking - CP Shehu Kabir Abubakar

xii. Border Patrol FHQ - CP Lawal Babatunde Ayodeji

xiii. Maritime Lagos - CP Emmanuel Agene

xiv. Admin Airwing - CP Jude M. Azuka

xv. Commandant Police College Kaduna - CP Dan Sabo Idi

xvi. Force Provost Marshal - CP Ibitoye Rufus Olajide

xvii. INEC - CP Adamu Ngojin Isa

xviii. Procurement DLS FHQ - CP Nwanosike Wodi Okocha

xix. PSO to IGP - CP Johnson Oluwole Adenola

xx. PAP Western Port Lagos - CP Olanrewaju Olawale Shola

xxi. Int’l Investigation INTERPOL - CP Shelleng Umaru Yusuf

xxii. SEB FCID Abuja - CP Emmanuel Aina

xxiii. Info-Tech ICT FHQ Abuja - CP Miller Gajere Dantawaiye

xxiv. Director NPF-NCCC - CP Henry Ifeanyi Uche

xxv. DOPS FHQ Abuja - CP Vungmoh S.M. Kwaimo

xxvi. Commandant Police College Ikeja – CP Fasuba A. Olabode