Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ó ṣeéṣe kí o dápé lọ́mọkùnrin ṣùgbọ́n kí o máà lè fún olólùfẹ́ rẹ lóyún? Ìdí rèé
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ó ṣeéṣe kí o dápé lọ́mọkùnrin ṣùgbọ́n kí o máà lè fún olólùfẹ́ rẹ lóyún? Ìdí rèé
Lara awọn ohun to maa n fa ikayasoke ati hilahilo laarin awọn lọkọlaya ni ọrọ ọmọ bibi. Gẹgẹbi aṣa ati igbagbọ ọpọ pe ọmọ ni ọpakutẹlẹ igbeyawo.
Ọpọ igba ni ayẹwo le fihan pe ara lọkọlaya ji perepere sibẹ ki wọn maa le e bimọ. Koda nigba ti iru awọn lọkọlaya bẹẹ ba lọ si ile iwosan, awọn dokita le maa le ri ohun kan pato tọka si gẹgẹbi bi okunfa airọmọbi wọn.
- bedsheet and your health: Ẹ wo ewu tó wà nínú lílo ‘’bedsheet’’ fún ìgbà pípẹ́
- Ṣé lóòtọ́? Bóo bá ń mu Garri jù tí wọ́n tàn ẹ́ pé ojú dídùn ni yóò gbẹ̀yìn rẹ; gbọ́ òótọ́ lẹ́nu onímọ̀
- Nǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára Cervical Cancer tí ìjọba Naijiria n pín fún àwọn ọmọbìnrin
- Perimenopause: Wo àwọn ọ̀nà mẹ́fà láti mójútó ìlera lásìkò tí nǹkan oṣù obìnrin ti fẹ́ dúró
Laipẹ yii ni faisiti Manchester ati Stockholm kede abajade iwadii kan pe o ṣeeṣe ki ara lọkọlaya da pe ki wọn si tun ni iṣoro ọmọbibi.
Lara awọn idi ti wọn ni ayẹwo iwadii wọn tọka si ni bi o ṣe ṣeeṣe fun ẹyin obinrin o maa dẹyẹsi awọn atọ ọkunrin kan, tabi maa yan iru atọ ọkunrin ti wọn fẹ ko sọ oun di ọmọ.
Ẹkunrẹrẹ alaye wa ninu fidio alalaye yii.






