Kò ṣée má gbọ̀ọ́
Nnkan ma lọrọ awọn akẹkọọ ileewe ẹkọṣe ọwọ to wa lorita Aperin n'Ibadan yii o
Mọkandinlọgọrin ninu wọn ni ọlọpaa ko logunjọ oṣu yii.
Lẹyin ti wọn kọlu ileewe girama CAC,Ita Aperin
Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Oyo, Johnson Adenola, fidi ẹ mulẹ pe dukia olowo nla ni wọn bajẹ.
Bẹẹ ọjọ ori awọn ọmọ naa ko to mejidinlogun.
Wọn ti ni wọn yoo de kootu laipẹ
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
Ṣe o mọ pe iye igba ti o n ṣegbọnsẹ lojumọ ni i ṣe pẹlu ilera rẹ
Emi o ma riyẹn ro o.
O kan ki oúnjẹ má ma dà bó ṣe yẹ ati jẹjẹrẹ inú ikùn.
Iwadi BBC pẹlu awọn onimọ nipa eyi,ṣalaye bi aiṣe igbọnsẹ deede ṣe le koba kindinrin, to si tun le fa ki eeyan maa gbagbe nnkan
Kan si BBC.COM/YORUBA fun ẹkunrẹrẹ
Nnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnn
Ara san, ina ṣẹyọ nileewe alakọọbẹrẹ Saint Peters, Igbemo Ekiti
Yara ikawe marun-un jona lọjọ Aiku to waye.
Ṣe ko mu ẹmi lọ
Rara
Igbakeji gomina, Monisade Afuye, ṣabẹwo sibẹ pẹlu ileri ọtun.
Nibo lawọn akẹkọọ ti n kawe bayii?














