Ìdí nìyíí tí ọkùnrin kò tíì lè lo òògùn ìfètòsọ́ͅmoͅbíbí títí di àsìkò yìí

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Itan to roͅ moͅ ifetosi oͅmoͅ bibi fun awoͅn oͅkunrin jeͅ itan to dun soͅ.
Ni igba awoͅn Giiki ni woͅn ti koͅkoͅ fi lede pe oͅkunrin to ba feͅ dena ati bimoͅ pe ki woͅn se nkan oͅmoͅkunrin ko gbona jainjain.
Amoͅ ni aye ode oni, iwadii imoͅ sayeͅnsi ti fi lede pe otitoͅ ni oͅroͅ naa.
Ile nkan awoͅn oͅmokunrin tutu ju gbogbo ara loͅ, to n si n da abo bo aatoͅ ọkunrin to n di oͅmoͅ.
Nitori naa ti agbegbe naa ba gbona ju bi o ṣe yeͅ loͅ, o ṣeeṣe ki nkan oͅmoͅkunrin naa ma gberi bi o se yeͅ.
Oͅna akoͅkoͅ ti awoͅn oͅkunrin n gba fi se ifeto si oͅmoͅ bibi ni lati maa weͅ omi gbigbona.
Ni oͅdun 1956, onimoͅ sayeͅnsi Matte Voegeli se awari pe ti oͅmoͅkunrin ba jojo si ori ohun to gbona to iwoͅn celcius meͅrinlelogoji 46.6C (116F), fun wakati marundinlaadoͅta fun bi oͅseͅ meͅta, igbagboͅ wa pe nkan oͅmoͅkunrin naa ko ni sͅisͅeͅ fun osu meͅfa, ti atoͅ reͅ ko si lee di oͅmoͅ.
Awoͅn omimoͅ ijinleͅ eto iwosan ni awoͅn ko lee fi eyi muleͅ, sugboͅn awoͅn kan ni ohun siseͅ daradara.
Ohun ti awoͅn dokita gbagboͅ wi pe o le da atoͅ oͅmoͅkunrin duro ni Vasectomy, amoͅ titi lai ni igbeseͅ yii.
Bi awoͅn onimoͅ ijinleͅ sayeͅnsi ṣe gbiyanju fun oͅpoͅloͅpoͅ oͅdun lati wa oogun ifeto si oͅmoͅ bibi fun awoͅn oͅkunrin

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ni oͅdun 1968 ni arakunrin kan loͅ fun ayeͅwoͅ loͅdoͅ onimoͅ nipa isesi eniyan nitori oogun kan to n lo, thioridazine lati fi setoͅju aisan oͅpoͅloͅ to n ba finra, ti jeͅ ki atoͅ oͅmoͅkunrin reͅ gbeͅ.
Amoͅ leͅyin oͅgboͅn oͅdun bayii, itan reͅ ti mu ireti ba awoͅn ominoͅ sayeͅnsi nipa oogun ti woͅn le lo lati fi se agbekaleͅ ifetosi oͅmoͅ bibi.
Bakan naa ni awoͅn oogun ti eni to b ani aisan eͅjeͅ riru ba n lo bii phenoxybenzamine le dena atoͅ oͅmoͅkunrin.
Ti awoͅn onimoͅ sayeͅnsi ba se aseyoͅri yoo roͅrun fun awoͅn obinrin naa lati se ifetosi oͅmoͅ bibi.
Awoͅn dokita to ti gbimoͅ loͅpoͅ igba lati gbe oogun naa sit ani woͅn jawoͅ reͅ nitori ipa to n ni lara awoͅn oͅkunrin.
Bakan naa ni igbiyanju si n loͅ loͅwoͅ lati gbe oogun naa jade amoͅ ipalara to wa nibeͅ ni ahun to n da awoͅn onimoͅ apoogun duro.
Iwadii naa tun fihan an pe ida ogun awoͅn oͅkunrin lo ni awoͅn ko ni de idi oogun naa, ti ida ogun naa si ni awoͅn yoo gbiyanju ati lo o, amoͅ awoͅn to ku ni awoͅn ko lee soͅ.















