Egungun Festival: Ẹ wo bí wọ́n ṣe ń ṣe ọdún eégún ní ìlú Benin Republic

Àkọlé fídíò, Egungun Festival: Ẹ wo bí wọ́n ṣe ń ṣe ọdún eégún ní ìlú Benin Republic

Ọdun egungun jẹ ọkan lara awọn ọdun to wọpọ ni ilẹ Yoruba, to si ni igba ati akoko ti awọn eegun yii ma n jade lati ṣe ọdun wọn.

Eyi lo mu wa lọ si ilu Iyoko ni orilẹede Republic of Benin nibi ti awọn eniyan ti pejọ ni ọgọọrọ lati ṣe ọdun egungun.

Eegun alagbaa ni olori eeguin ni agbegbe naa, ti wọn si ni etutu ti wọn ma n ṣe fun gbogbo eegun to ba jade ki ilu le tuba, ki o si tuṣẹ.

Ẹ wọ ẹkunrẹrẹ fidio bi awọn eegun naa sẹ n dabira.