El Salvador Mega Prison: Àlàyé rèé lórí ìdí tí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ èèyàn ṣe wọ ọgbà ẹ̀wọ̀n

Awọn igun afurasi ọdaran akọkọ toto ẹgbẹrun meji ni El Salvador ni wọn ti ko lọ sinu ọgba ẹwọn tuntun lẹyin ti Aarẹ Nayib Bukele kede igbogun ti iwa bajẹ lorilẹede naa.

Ogunlọgọ afurasi ọdaran ni ọwọ tẹ lẹyin ti ijọba kede ilu ofarọ lorilẹde naa lori iṣekupani ati awọn iwa ọdaran miiran.

Ọgba ẹwọn naa yoo gba eeyan to ju ẹgbẹrun lọna ogoji lọ.

Aworan oke yii lo safihan bi awọn ẹlẹwọn pẹlu ẹsọ tatto lara wọn, se n wọ le si ọgba ẹwọn pẹlu sẹkẹsẹkẹ lọwọ ati ẹsẹ wọn.

Awọn janduku n duro lati wọ ninu atimọle wọn lẹyin ti ijọba ko ẹgbẹrun meji ẹlẹwọn lọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn ẹlẹwọn naa ni wọn joko si ilẹlẹ, ti wọn si kawọ le ori wọn, ki wọn to ko wọn atimọle wọn.

Awọn ẹlẹwọn duro pe ki wọn kowọn lọ si atimọlẹ lẹyin ti awọn ẹgbẹrun meji balẹ ọgba ẹwọn tuntun Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé fídíò, Wo fọran bi wọn ṣe ko awọn ẹlẹwọn naa wọle

Aarẹ Bukele gbe sori ayelujara Twitter pe awọn igun ẹgbẹrun meji akọkọ ni wọn ti ko lọ si ọgba ẹwọn naa, eyi to ni ohun lo tobi julọ ilẹ Amẹrika.

"Eyi ni yoo jẹ ile wọn tuntun, wọn yoo wa nibi fun ọpọlọpọ ọdun, ti wọn ko si ni anfani lati ṣe akoba fun awujọ."

Awọn asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Ọgba ẹwọn to tobi naa lo wa ni Tecoluca, agbegbe ti ko jina si guusu iwọ oorun olu ilu El Salvador, o ni ile gbe mẹjọ.

Ikọkan awọn ilegbe yii ni atimọle mejilelọgbọn, to si le gba ju ọgọrun un ẹlẹwọn gẹgẹ bii ijọba ṣe kede.

Atimọle ni ile igbẹ mejeeji.

Awọn ẹlẹwọnn n duro lati wọ atimọle wọn tuntun lẹyin ti ijọba ko wọn ọgba ẹwọn tuntun Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn asọ ọgba ẹwọn n mojuto bi awọn janduku bi ẹgbẹrun meji ṣe n bọ silẹ kuro ninu bọọsi akero bọ si ọgba ẹwọn Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn ẹlẹwọnn n duro lati wọ atimọle wọn tuntun lẹyin ti ijọba ko wọn ọgba ẹwọn tuntun Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Aarẹ Bukele kede ogun loei awọn janduku naa ninu oṣu kẹta ọdun to kọja, to si buwọlu iwe ofin eyi ti afikun le ba ni ọpọ igba.

declared a "war on gangs" last March, passing emergency measures which have been extended several times.

Ofin naa lo fun awọn agbofinro lati mu ẹnikẹni liasi iwe ofin, eyi to mu adikun anfani ti awọn eeyan ilu naa.

Awọn ẹlẹwọnn n duro lati wọ atimọle wọn tuntun lẹyin ti ijọba ko wọn ọgba ẹwọn tuntun Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

Awọn ẹlẹwọnn n duro lati wọ atimọle wọn tuntun lẹyin ti ijọba ko wọn ọgba ẹwọn tuntun Terrorism Confinement Center

Oríṣun àwòrán, Reuters

O to ẹgbẹrun lọna mẹrinlelọgọta afurasi ti ọwọ agbofinro ti tẹ ninu igbogun ti iwa ibajẹ naa,

Awọn alasẹ ni awọn janduku bi-MS-13 ati Barrio-18 lo sokufa ọpọlọpa iwabajẹ lorilẹede naa. idi kan pataki ti ijọba fi gbogun ti awọn janduku naa ni lati kọgba wọn patapata.

Ajọ to n risi ẹtọ ọmọ niyẹni ti kominu pe ọpọ igba ni awọn eeyan ti ko mọdi n jẹya nitori ofin naa. ti awọn mmiran ti ijọba mu ti ṣe ọpọlọpọ ijamba fun awọn araalu.

Igbesẹ Bukeke lati gbogun ti iwa ọdaran lo ti ilumọka laarin awọn araalu ati gbogbo agbaye .