Valentine: Ọkùnrin ní kí obìnrin má fún àwọn ní àwọ̀tẹ́lẹ̀ mọ́ bíi ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́
Ọjọ Kẹrinla, osu keji ọdọọdun ni awujọ agbaye maa n se ajọyọ ọjọ ololufẹ, eyi ti ko yọ orilẹede Naijiria silẹ.
Idi ree ti BBC Yoruba fi tọ tọkọtaya kan lọ lati mọ ero wọn nipa ayajọ ọhun.
Wọn salaye pe ọjọ naa wa lati fi ifẹ kan si gbogbo eeyan ni, kii se fun ọrẹbinrin abi ọrẹkunrin nikan.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Àwọn ǹkan ti ọ̀pọ̀ ko mọ nípa Baba Suwe
- Tí o bá ń pẹ́ jẹun alẹ́, o lè ní àrùn jẹjẹrẹ ọyàn àti asétọ̀
- Ẹ̀yin òṣèrè tíátà, ẹ ní ṣùúrù de àsìkò Ọlọ́run, ẹ máṣe kánjú kọjá kádàrá - Madam Ṣajẹ
- Ìdí tí mo fi ní ọ́jọ́ ikú ni ọ̀la ọjọ́ 'Valentine' fún àwọn kan- Mike Bamiloye
- Ìpínlẹ̀ Oyo, Ogun, Ondo buwọ́lu àbádòfin Àmọ̀tẹ́kùn
Wọn wa rọ awọn obinrin lati fi òdòdó ṣe ẹ̀bùn ọjọ́ olólùfẹ́ fún ọkùnrin dípò ko gbà lati jẹ kó já òdòdó ara oun.










