Nigeria governorship election result: Wo àkọsílẹ̀ iye ìbò tí gómìnà Sanwoolu, Makinde, Dapo àti Abdulrazaq gbà

Gẹgẹ bi eto idibo ati ikede awọn ajaweolubori ṣe ti wa sopin ni ọpọlọpọ awọn ipinlẹ Naijiria, ẹrọ BVAS ati IREV ti ajọ INEC n lo naa ti ṣiṣẹ wọn lati ko gbogbo esi idibo sori ayelujara.
Ajọ eleto idibo lorilẹede Naijira, INEC ti fi awọn esi idibo sọwọ sita nipa eto idibo gomina ati tile asofin to waye.
Ọjọ Satide, ọjọ kejidinlogun osu Kẹta ọdun 2023 lawọn eto idibo naa waye.
Awọn maapu isalẹ yii lo n ṣe afihan awọn esi ibo ti ajọ INEC kéde ni Kwara, Eko, Ogun àti Oyo:
Maapu yii lo n se afihan esi ibo ni ipinlẹ Kwara:
Ó ṣeéṣe kí ẹ̀rọ ti ò n lò ma fọwọ́ sí ohun tóò fẹ́ wò yìí
Maapu yii lo n se afihan esi ibo ni ipinlẹ Eko:
Ó ṣeéṣe kí ẹ̀rọ ti ò n lò ma fọwọ́ sí ohun tóò fẹ́ wò yìí
Maapu yii lo n se afihan esi ibo ni ipinlẹ Ogun:
Ó ṣeéṣe kí ẹ̀rọ ti ò n lò ma fọwọ́ sí ohun tóò fẹ́ wò yìí
Maapu yii lo n se afihan esi ibo ni ipinlẹ Oyo:
Ó ṣeéṣe kí ẹ̀rọ ti ò n lò ma fọwọ́ sí ohun tóò fẹ́ wò yìí
Eto idibo yii waye kaakiri orilẹede Naijiria ni ipinlẹ mejidinlogun ti esi gbogbo awọn ipinlẹ ọhun si jade latọdọ ajọ INEC.
Bi ajọ INEC se n kede awọn esi ibo naa yika orilẹede Naijiria lo wa ninu Maapu isalẹ yii.
Ó ṣeéṣe kí ẹ̀rọ ti ò n lò ma fọwọ́ sí ohun tóò fẹ́ wò yìí