You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Judy Austin Moghalu: Mo ti 'ùnfollow' ẹ lórí 'social media'; Ọlọ́run a ṣe idajọ fún ẹyin méjèèjì- Iyawo Yul-Edochie
Oriṣa jẹ n pe meji obinrin kii fi igba gbogbo denu ni awọn agba n wi.
Ni kete ti gbadugbaja osere Nollywood ni, Yul-Edochie ṣe ìkéde nla lori oju opo instagram rẹ̀ eyi to ti n jẹ ki ẹjọ pọ lori ayelujara bayii.
Nibẹ lo ti ni pé òun ti bí ọmọ ọmọkùnrin pelu akegbe ẹ nínú ìṣe osere, iyẹn Judy Austin ti o pe ni ìyàwó rẹ kejì.
- 'Aláàfin ti rí ikú rẹ̀ ṣáájú ọjọ́ tó wàjà, ó sọ̀rọ̀ sílẹ̀ kó tó kú'
- Wo àwọn òrékelẹ́wà tí yóò ṣe opó lẹ́yìn Aláàfin Oba Adeyemi tó papòdà
- Ìgbẹ́jọ́ Ilànà Ọmọ oodua àti Náìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ nílé ẹjọ́ ní Ekiti
- 'Ẹran ẹtu ni mo yìnbọn sí, àmọ́ òkú ìmáàmù ni mo bá nígbà tí mo fẹ́ gbe e'
- Ẹ yé fi ìpapòdà àwọn lọ́balọ́ba ìpínlẹ̀ Oyo kọmi lọ́rùn - Gómìnà Seyi Makinde
- "Kòríkòsùn lèmi àti Alaafin ṣùgbọ́n kété táwọn kan kẹ́ẹ́fín pé èmi láàyò ni gbogbo nǹkan dojúrú." Badirat Ajoke, olorì tẹ́lẹ̀ kẹ́dùn Alaafin
- Wo ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwọn olòrì Alaafin Adeyemi àtàwọn tó bá fẹ́ fẹ́ wọn
- Mo ti gbà báyìí pé ohun gbogbo tó n dán kọ́ ni wúrà - Olori Badirat Adeyemi
- Ìjọba àpapọ̀ ṣí ẹnubodè Idiroko àti àwọn mẹ́ta mìíràn, wo ohun tí BBC bá bọ̀ níbẹ̀
Kini esi iyale Yul Edochie?
Ni kete ti Iyawo akọfẹ Yul Edochie ka ikede ọkọ rẹ lori ayelujara yii ni oun naa ti daa pada fun un.
May Edochie fe sì pe Ọlọrun ó ṣe idajọ fún àwọn méjèèjì.
May Edochie ni ó jé ìyàwó àkókò fún gbadugbaja osere naa ti o si bí ọmọ merin fún un.
Yul-Edochie ninu kéde to gbé sì ayélujára instagram ni ojoru sọ pé òun ti bí ỌMỌKÙNRIN.
O ni pe: "ọrùko ọmọ mi jẹ STAR DIKE MUNACHIMASO YUL-EDOCHIE tí ìyàwó mi kejì Judy Austin bí fún mi, mo ní ìfẹ́ ọmọ náa gege bí mo ṣe ni ifẹ àwọn ọmọ yòókù."
Bawo ni irinajo igbeyawo awọn mejeeji?
Lọdun 2004 ni May Yul Edochie fẹ Yul Edochie to jẹ ọmọ agba ọjẹ oṣere ni, Pete Edochie.
Lọdun to kọja ni wọn ṣe ayeye ọdun mẹtalelogun ti wọn ti jọ wa papọ.
Yul ati May bi ọmọ mẹrin fun ara wọn, Adẹ\daa fun wọn ni obinrin kan ati ọkunrin mẹta
Leyin ikede ni awọn eeyan tii fọhun sita pe...
Leyin ikede yii ni ero awọn ọmọ Naijiria ti ṣọtọọtọ si igbeyawo aya meji.
Bayii ti iyawo keji naa ti bi ikoko, ọmọ Yul Edochie ti di marun un bayii.
Koda, ninu awọn ọmọ yul ti wa nile ẹkọ giga bayii.