Wo àwọn ohun tí o kò kà sí nípa mátírẹ́sì tí o ń sùn, ṣùgbọ́n tó ń ní ipa nínú ayé rẹ
Ṣe o n ni iṣoro ati sun ni, o ṣeeṣe ko nii ṣe pẹlu irufẹ timutimu ibusun ti o nlo eleyi ti oyinbo n pe ni matiresi.
Ibusun to ba ni itura gbogbo to yẹ yoo maa mu ki o sun asunnara ni, ti o ko si ni maa ji nigba gbogbo pẹlu iṣoro airoorun sun tabi aarẹ gbogbo rikerike ara rẹ.
Awọn onimọ ti fi idi rẹ mulẹ pe bi eeyan ba fẹ maa ni ilera pipe, irufẹ orun ti onitọhun ba n sun nii ṣe pupọ lori rẹ. Matirẹẹsi si nii ṣe lọpọlọpọ lara bi a ṣe n sun daadaa si bẹẹni ọpọlọpọ lo n foju rena rẹ.
- Lẹyìn tí UK yọ Nàìjíríà kúrò lórí ''red-list'', wo ìlànà tuntun t'ọ́mọ Nàìjíríà lè fi gba Visa
- Àmọ̀tẹ́kùn rápálá wọ àdúgbò láti bá ìdílé kan lálejò, Ọwọ́ òfin tẹ̀ ẹ́
- 'Ògì ni mó rán Demilade lọ rà, ẹ̀ṣẹ̀ táa ṣẹ Pásítọ̀ Mr Olajiga kò yé mi tó fi gé òkú ọmọ wa wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́, ẹ gbà mí ooo!'
- BBC Africa Eye tú aṣírí ẹgbẹ òkùnkùn Black Axe ní Nàìjìríà, ìpànìyàn àti àwọn olóṣèlú tó wà lẹ́yìn wọn
- Àwọn ọ̀rẹ́ mi lè fún mi ní 'One, one million' àwọn ọ̀rẹ́ ti yín ń kọ́? Kie kie ti sọ̀rọ̀sókè fún BBC Yorùbá
- Wọ́n gé gògòńgò ìyá wa lọ lẹ́yìn tí wọ́n pa a- Omo Iya Deeper Life
- Ṣé lóòtọ́ ní pé ìlúmọ̀ọ́ká agbábọ́ọ̀lù ayé àtijọ́ Teslim Thunder Balogun gbá ṣọ́ọ̀tì gbígbóná fi pa "Goal keeper"?