PDP Convention: Àrà ọ̀tọ̀ ní ìdìbò 'convention' tọ̀tẹ̀ yí, òru mọ́jú la ti yanjú ọ̀rọ̀ lórí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ipò -Seyi Makinde
Ipo mọkanlelogun ni wọn yoo wa awọn eeyan tuntun ti yoo maa tukọ ẹgbẹ naa si, eeyan bii mẹtadinlọgbọn ni yo si maa du ipo naa.
Gomina Makinde ni mejidinlogun ninu awọn ipo naa ni wọn ti yanju eeyan ti yoo diimu ni tubiinubi.
- Ìpàdé ìdìbò 'convention' ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ń gbìnàyá l'Abuja
- Ìjíròrò tó wáyé láàrín Bola Tinubu àti Igbákejì ààrẹ Yemi Osinbajo, ohun tí a rí gbọ́ nípa rẹ̀ nìyí
- Òṣì pọ̀ nínú PDP ni Makinde fi ń ra ọkọ̀ àlòkù fọ́mọ́ ẹgbẹ́, tí yóò tún gbe sórí ayélujára - Olopoeyan
- Olusegun Mimiko àti ẹgbẹ́ rẹ̀, ZLP darapọ̀ mọ́ PDP
- Kò yẹ kí àwọn òjíṣẹ́ Ọlọ́run máa kiri ilé ìjọba, kí ni wọ́n ń wá? - Timi Osukoya