Prince Phillip: Ìgbé ayé Ọmọba Phillip nínú àwòrán

Duke ti Edinburgh lọdun 1977
Àkọlé àwòrán, Wọn bi Duke ti Edinburgh ni Greek island ti Corfu ni ọjọ kẹwa oṣu kẹfa ọdun 1921. Awọn iran rẹ jẹ idile oye lati Denmark, Germany, Russia ati Britain.
1px transparent line
Philip ni kekere

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Philip ni ọmọkunrin kanṣoṣo ti Ọmọba Prince Andrew ti Greece ati Ọmọbabinrin Alice ti Battenberg bi.
PrinAarẹ ni ọmọdekunrin keji lati apa alafia

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ bẹrẹ ileewe ni France ni ileewe MacJannet American school ni St Cloud oun si niyi pẹlu awọn akẹgbẹ rẹ nileewe. Ọmọ ọdun meje lo lo lọ gbe pẹlu awọn mọlẹbi rẹẹ Mountbatten ni England, nibi to ti ka ileewe to ṣaaju alakọbẹrẹ.
Arẹmọ Phillip lọmọ ọdun 16

Oríṣun àwòrán, PA

1px transparent line
Duke ti Edinburgh ni Royal Navy, Portsmouth

Oríṣun àwòrán, PA

1px transparent line
Imana Ọmọbabinrin Elizabeth pẹlu Lieutenant Philip Mountbatten

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Nigba ti oun ati Ọmọbabinrin Elizabeth bẹrẹ - July 1947...
1px transparent line
wọn ṣegbeyawo ni ogunjọ oṣu kọkanla ọdun kan naa

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Bẹ́ẹ̀ si ni wọn ṣegbeyawo ni ogunjọ oṣu kọkanla ọdun kan naa
Queen Elizabeth II, pẹlu Duke ti Edinburgh ni Treetops, Kenya 05/02/52circa

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth ati Duke ti Edinburgh lọjọdiẹṣaaju ọjọ to gbọ iroyin pe baba rẹ ti ku
1px transparent line
Arẹmọ Phillip

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ n ṣe ere idaraya Polo
Arẹmọ n gba bọọlu Cricket

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ tun fẹran ko maa gba bọọlu Cricket
Arẹmọ Phillip kọwọ rin pẹlu Ọbabinrin Elizabeth lọ si India lọdun 1961.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip kọwọ rin pẹlu Ọbabinrin Elizabeth lọ si India lọdun 1961.
1px transparent line
Arẹmọ Phillip pẹlu Ọbabinrin Elizabeth ati ọmọ wọn mẹrin
Àkọlé àwòrán, The duke and Queen had four children, (from left) Edward, Andrew, Anne and Charles, pictured here in the 1960s.
Arẹmọ Phillip pẹlu Ọbabinrin Elizabeth ṣe ibẹwo si oko kan lati ṣe ayẹyẹ igbeyawo wọn

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip pẹlu Ọbabinrin Elizabeth ṣe ibẹwo si oko kan lati ṣe ayẹyẹ igbeyawo wọn
Arẹmọ Phillip ati Ọbabinrin Elizabeth nigbato n ṣe ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹẹdọgbọn

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip ati Ọbabinrin Elizabeth nigbato n ṣe ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹẹdọgbọn
Arẹmọ Phillip pẹlu Ọbabinrin Elizabeth

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip pẹlu Ọbabinrin Elizabeth
Oṣu kẹjọ ọdun 1979 nigba ti ọmọ ẹgbọn/aburo baba rẹ ku

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Oṣu kẹjọ ọdun 1979 nigba ti ọmọ ẹgbọn/aburo baba rẹ ku
Duke ti Edinburgh jokoo lori Erin ni ibẹwo rẹ si Kanha Game Reserve, 1983

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ fẹran awọn ẹranko ati nkan ti Ọlọrun da pupọ
Arẹmọ Wales Ọmọbabinrin Wales, ikoko Ọmọba Harry, Ọmọba William, Duke ti Edinburgh, Ọmọba Edward, Ọbabinrin Elizabeth II ati Ọmọbabinrin Anne ni baakoni aafin Buckingham Palace, London

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, In 1985 the Duke of Edinburgh was surrounded by his family, including the young princes William and Harry, as they gathered to watch a flypast over Buckingham Palace after Trooping the Colour.
Lọdun 1996 Duke kọwọrin pẹlu aarẹ South African President Nelson Mandela

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Lọdun 1996 Duke kọwọrin pẹlu aarẹ South African President Nelson Mandela lọ fun yiyan bi ologun awọn ẹlẹṣin lọjọ ibẹwo akọkọ rẹ si Britain.
Arẹmọ Phillip kọwọ rin pẹlu Ọbabinrin Elizabeth lọ si ọja

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip gbaruku ti Ọbabinrin fun o le ni ọgọta ọdun iṣejọba rẹ to fi mọ igba to pe ẹni aadọta ọdun lọdun 2002
Duke ti Edinburgh

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Duke ti Edinburgh nibi ami ẹyẹ Duke of Edinburgh
Duke tẹsiwaju lati maa ṣe idije ere ẹṣin koda titi di igba ogbo rẹ.

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Duke tẹsiwaju lati maa ṣe idije ere ẹṣin koda titi di igba ogbo rẹ. Ọkan ree ni Sandringham lọdun 2005.
Igbeyawo ọmọ-ọmọ Arẹmọ Phillip, Ọmọba Prince Williams pẹlu Catherine Middleton lọdun 2011.

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Igbeyawo ọmọ-ọmọ Arẹmọ Phillip, Ọmọba Prince Williams pẹlu Catherine Middleton lọdun 2011.
Arẹmọ Philip, Duke ti Edinburgh

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Lẹyin oṣu mejila, o fihan pe ṣaka ni ara Duke ti Edinburgh ṣi da
Arẹmọ Phillip àti ọmọbabinrin Anne

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Arẹmọ Phillip àti ọmọbabinrin Anne lẹyin ti ara Duke ti ya
1px transparent line
June 2013 ni ṣọọṣi kan ni Westminster Abbey lati ṣe ayẹyẹ iwuye ọgọta ọdun ti Ọbabinrin pe lori oye

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, June 2013 ni ṣọọṣi kan ni Westminster Abbey lati ṣe ayẹyẹ iwuye ọgọta ọdun ti Ọbabinrin pe lori oye
Ọbabinrin Elizabeth ati Arẹmọ Phillip ni ZSL Whipsnade Zoo

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Lẹyin to ṣi ibudo ọsin ati igbafẹ awọn Erin, Duke ti Edinburgh kede pẹ̀lú atilẹyin Ọbabinrin pe oun ko ni farahan ni eto itagbangba kankan mọ lẹni ọdun marundinlọgọrun to pe
Ọbabinrin Elizabeth ati Arẹmọ Phillip

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth ati Arẹmọ Phillip
Dke ni ọkọ Ọbabinrin to pẹ laye ju ninu itan ilẹ Britain

Oríṣun àwòrán, PA Media

Àkọlé àwòrán, Dke ni ọkọ Ọbabinrin to pẹ laye ju ninu itan ilẹ Britain