NERC Electricity Tariff: àfikún owó iná 'tariff' làti N2 sì N4 la ṣé dipo ìdá 50% tàwọn èèyàn n sọ́

Oríṣun àwòrán, NERC
Ko si ootọ ninu ọrọ pe a ti fikun iye owo tarifu mọnamọna tawọn ara ilu n san.
Ikede yi lo waye lati ọdọ ajọ to n mojuto ọrọ ina mọnamọna ni Naijiria, NERC.
Loju opo Twitter ileeṣẹ naa ni wọn fi ọrọ yi si ti wọn si ni awọn ko fi kun iye owo tawọn to n jẹ anfaani ina wakati mejila lojumọ n san iyẹn awọn to wa ni akasọ D ati E.
Ni itẹsiwaju alaye ajọ naa wọn ni afikun to waye ko ju alekun lati Naira meji si Naira mẹrin fun Kilowat kan laarin wakati kan fawọn to wa lori akasọ A B C D ati E.
Ohun ti wọn lo fa alekun yi ko ju bi igbowolori nkan lọja ti ṣe n waye ati iye owo dọla ti ko duro loju kan.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Alaye yi ti wọn lawọn ṣe lati tako iroyin ẹlẹjẹ to n ja rain pe awọn ṣe afikun ida aadọta ninu ida ọgọrun iye owo ina tara ilu n san koba awọn eeyan lara mu.
Idi ni pe agbeyẹwo afikun ti wọn lawọn ṣe yi(N2.00-N4.00) fi han pe o ju ida aadọta ti wọn n tako pe kii ṣe ootọ.
Koda ida ọgọrun ni wọn ṣe eyi to ju iye tawọn oniroyin gbe jade lọ.
Kia lawọn eeyan ti n tọka si ohun ti wọn n sọ yi ti wnsi ni ati aadọta ati ọgọrun, nigba wo ni wọn sọ fun ara ilu ki wn to ṣe afikun?
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4

End of X post, 5