Genotype: Kí làwọn àǹfàni àti ewu tí ẹ̀yà jínótáìpù rẹ le mú bá ìgbé ayé rẹ̀?

Àkọlé fídíò, Genotype: Kí làwọn àǹfàni àti ewu tí ẹ̀yà jínótáìpù rẹ le mú bá ìgbé ayé rẹ̀

Ọpọ eniyan lo n gbe igbe aye wahala nitori aimọkan wọn lori jinitaipu wọn. irufẹ igbesẹ bẹẹ tilẹ tun ti fa ipalara fun ọjọ ọla ọmọ wọn.

Eyi ni ohun ti eto laa han mi gbe yẹwo lọtẹ yii.