Amotekun: Ìdí táwọn àgbà Nàìjíríà fi ń forí gbárí àti ohun tó yẹ
Ṣé ẹ rántí pé lọ́jọ́ kẹwa oṣu kinni ni awọn gomina iha Guusu-Iwọ Oorun Naijiria korajọ ni ipinlẹ Oyo lati ṣe ifilọlẹ ikọ alaabo Amotekun.
Labẹ akoso Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu gẹgẹ bii adari, o ti wa delẹ bayii ṣugbọn o tun da bi ẹni pe awọn kan o fẹ lọwọ si i to si jẹ pe pataki ni wọn ninu ọrọ to wa nilẹ yii.

Ẹwẹ, fun iranti yin:
1. Amotekun ni akọkọ ikọ alaabo tawọn gomina pawọpọ lati da silẹ ọkan lara awọn ẹkun Naijiria
2. Lóòtọ́ ofin Naijiria ko sọrọ kankan nipa idasilẹ ikọ alaabo ẹlẹkun jẹkun pe ọwọ Ọlọpaa nikan ni aabo araalu wa, ha, awọn eeyan ilu si ni ipa Ọlọpaa ko ka aabo ilu pẹlu gbogbo ohun tawọn n ri.
Abalọ aba bọ, gbogbo awọn tọrọ kan ṣaa jọ jokoo jiroro nilu Abuja pẹlu ileeṣẹ Aarẹ Naijiria.
Wọn si ti fẹnu ko lori ọrọ itẹsiwaju ikọ naa.
- Ṣé Coronavirus leè tẹ̀lé ọjà Chinco wọ Nàìjíríà? Ìdáhún àtàwọn ìbéèrè míì
- Ẹ̀yin obìnrin tẹ́ẹ fẹ́ wá bímọ ní America, ọ̀nà ti tì pa látònì! - Trump
- Ẹyin ni wọ́n fi n gba ìbále ẹlòmiran lára wa ki a to lọ pàde àwọn oníbara
- Ìbọn kọ́ ni wọn fi pa èèkàn ẹgbẹ́ APC n‘Ibadan, ọ̀bẹ ni wọ́n fi gé iṣan ọrùn, ọrùn ọwọ́ àti ẹsẹ̀ rẹ̀ - Ọlọ́pàá
- Yaba Left: Àṣírí tú! #7000 sí #10000 ni owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fún bẹẹdi ní ilé àwọn aláìsàn ọpọlọ