Police brutality during lockdown: Nínú Ọlọ́pàá àti Coronavirus, èwo gan an laráàlú ń bẹ̀rù jùlọ?

Àkọlé fídíò, Lockdown in Africa: Nínú Ọlọ́pàá àti Coronavirus, èwo gan an laráàlú ń bẹ̀rù jùlọ?

Kaakiri agbaye ni wahala awọn ọlọpaa ti n waye koda eyi ko ys awọn orilẹ€de ti aye n fi oju wo pe wọn ti goke agba silẹ.

Gẹgẹ bi iwadii kan eyi ti Journal of Epidemiology and community health gbe jade lọdun 2018, eeyan ẹgbẹrun kan ati mẹrindinlaaọjọ (1,146) ni ẹmi wọn ti ọwọ ọlọpaa bọ lọdun 2015 ti ẹgbẹrun kan o le mejidinlaadọfa (1, 092) miran si tun ku lọwọ ọlọpaa lagbaye lọdun 2016.

Eyi ni fidio wahala awọn ọlọpaa lasiko coronavirus eleyi to mu ẹmi ọpọ lọ pẹlu.