Restructuring: Àgbékalẹ̀ orílẹ̀èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ yìí kò lè fàyè ìdàgbàsókè sílẹ̀ fún ẹ̀yàkẹ́yà-Ọ̀jọ̀gbọ́n Banji Akintoye
Ọjọgbọn Banji Akintoye ni aṣiwaju ẹya Yoruba lọwọ yii, nitorinaa obi ọrọ nipa bi idagbasoke ẹya Yoruba yoo ṣe kẹsẹjari gbo ni ẹnu rẹ.
Idi si ni yi ti BBC News Yoruba fi tọọ lọ fun iṣiniye lori awọn igbesẹ to n lọ lọwọ nipa idagbasoke ẹya Yoruba, orilẹ-ede Naijiria ati ajakalẹ arun coronavirus to n fẹju koko kaakiri agbaye bayii.
- Owó tó kàn mí nínú N4 mílíọ̀nù ìbejì Akeugbagold tí a jí gbé, bàtà ni mo fi rà-Afunrasí
- "Ọ̀pọ̀ ènìyàn tó ń gbé ní Eko, Ibadan, Osogbo ló ti kú..."
- Ṣé òótọ ni pé èèyàn leè kó Coronavirus láti ara aṣọ tàbí bàtà?
- Darandaran tí mo mọ̀ wà lára àwọn tó ṣá mi ní àdá-Ọlọ́kadà
- Ṣé ìwọ leè wa kẹ̀kẹ́ lórí ìgò? Wo bí àwọn ọmọ yìí ti ń ṣe é