Ṣé òótọ ni pé èèyàn leè kó Coronavirus láti ara aṣọ tàbí bàtà?
Ọna kan gboogi ti arun Covid-19 fi n wọ ara eeyan ni lati ẹnu, imu tabi oju.
Awọn kan ti wa n bere pe n jẹ o ṣeṣẹ ki eeyan ko arun ọhun lati ara aṣọ tabi bata ti eeyan ba wọ.
Lootọ ni pe eeyan le ko arun Coronavirus lati ara ohun ti arun naa ba wa, bii ori tabili, aga iojoko tabi nnka mii.
- Kó má a lọ bẹ̀ ẹ́ ní ìséde coronavirus fún ọ̀sẹ̀ méjì míràn - Ìjọba Nàìjíríà
- Owó tó kàn mí nínú N4 mílíọ̀nù ìbejì Akeugbagold tí a jí gbé, bàtà ni mo fi rà-Afunrasí
- Wo ipa tí ìlànà tuntun tí ìjọba Eko gbé jáde lórí Covid-19 yóò nìí ní ìgbésí ayé rẹ
- Bàbá mi fún mi ní kíndìnrín rẹ̀ láti dóòlà ẹ̀mí mi- Sam
Ṣugbọn ṣe o ṣeṣẹ ki eeyan lugbadi arun Coronavirus lati ara aṣọ tabi bata?
Ẹ wo fidio yii fun alaye ni kikun.