Coronavirus in Nigeria: Ǹjẹ́ àwọn arúgbó nìkan ni ààrùn coronavirus ń mú?
Oriṣiiriṣii nnkan lawọn eeyan n sọ nipa aarun coronavirus to n ṣọṣẹ kaakiri gbagbo agbaye bayii.
Awọn kan gbagbọ tẹlẹ pe awọn oyinbo alawọ funfun nikan ni aarun n mu wi pe kii mu awọn alawọdudu ilẹ Afirika.
Awọn miiran tiẹ sọ awọn arugbo lo n mu, kii mu awọn ọmọde.
Loju awọn mii, aarun olowo ni coronavirus jẹ, kii mu talika.
BBC Yoruba ṣe alaye lẹkunrẹrẹ lori igbagbọ awọn kan pe awọn arugbo ni covid-19 maa n mu.
- Ǹjẹ́ ààrùn olówó ni coronavirus bí?
- Ǹjẹ́ òògùn vitamin C lè pa coronavirus?
- Kínni ìtàkùn ayélujára 5G nííṣe gan na pẹ̀lú ààrùn coronavirus?
- Bí mo ṣe jàjà bọ́ lọ́wọ́ àrùn Coronavirus rèé- Ayodeji Osowobi
- Kí làwọn iléèwòsàn ń ṣe láti dáàbò bo ara wọn àti aláìsàn tí wọ́n ń tọ́jú?
- Òfìfo ṣọ́ọ̀ṣì pa aṣọ dà fún àwọn Páṣítọ̀ Nàìjíríà