World health day 2020: Kí làwọn iléèwòsàn ń ṣe láti dáàbò bo ara wọn?

Àkọlé fídíò, World health day 2020: Kí làwọn iléèwòsàn ń ṣe láti dáàbò bo ara wọn

Ọrọ Coronavirus to wa nita bayii kan gbogbo mutumuwa koda awọn oṣiṣẹ eto ilera gan an ko jafira lori rẹ.

Ọjọ Iṣẹgun ni ayajọ ilera lagbaye, BBC Yoruba gbe ọrọ yẹwo lori bawọn oṣiṣẹ eto ilera nileewosan ṣe n daabo bo ara wọn lasiko yii.

Abọ ree nini fidio wa to wa loke yii.