Coronavirus in Nigeria: Ayodeji Osowobi ṣàlàyé bí ó ti jàjà bọ́ lọ́wọ́ àrùn covid-19
Arun Coronavirus ti pa ẹgbẹgbẹrun eniyan kaakiri agbaye, ti o si ti sọ ọpọ di alailara.
Amọ bi arun naa ṣe buru to, awọn eniyan miran ṣi n ru ye, ti wọn si n sọ iriri wọn.
Lara wọn ni arabinrin Ayodeji Osowobi to ko arun Coronavirus, to si ri iwosan gba lorilẹede Naijiria.
Ẹ gbọ iriri rẹ:
- Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ya bo ibùdó ìdìbò láti gba oúnjẹ Coronavirus
- Òfìfo ṣọ́ọ̀ṣì pa aṣọ dà fún àwọn Páṣítọ̀ Nàìjíríà
- Afunrasí ẹ̀sùn jìbìtì ló ni iléeṣẹ́ tó ń ṣe ìwé àṣẹ wọléwọ̀de ní Nàìjíríà
- Òfìfo ṣọ́ọ̀ṣì pa aṣọ dà fún àwọn Páṣítọ̀ Nàìjíríà
- Èèyàn 16 míràn tún ti ní àrùn Coronavirus ní Naijiria
- Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ya bo ibùdó ìdìbò láti gba oúnjẹ Coronavirus