Human trafficking: Iṣẹ́ irun ṣíṣe ló di iṣẹ́ aṣẹ́wó mọ́ Adeola lọ́wọ́ ní Cote D'ivoire
Ijinji Adeọla, (kii ṣe orukọ abisọ rẹ) ilepa atidagbasoke ati atila laye lo fọkan si ko to di pe irinajo ẹda jaa ni tanmọọ.
Iṣẹ aje lo ba lọ soke okun labẹ Ẹtan pe yoo lọ kọ iṣẹ yoo si ko ẹru ati ẹru wale ṣugbọn nigba to de orilẹede Cote d'Voire ni o to han si pe iṣẹ aṣẹwo ni wọn mu oun wa ṣe.
- Ìjọba Ondo ṣetán láti san #30,000 gẹ́gẹ́ bí owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ
- 'Ẹ yé mu gaàrí mọ́, tẹ́ẹ̀ bá fẹ́ lùgbàdì ibà Lassa'
- Fífẹ́ ju ìyàwó kan lọ ló mú ìṣẹ́ àti ìfàsẹ́yìn ba àpá àríwá Nàìjíríà- Lamido Sanusi
- Ṣé Coronavirus leè tẹ̀lé ọjà Chinco wọ Nàìjíríà? Ìdáhún àtàwọn ìbéèrè míì
- Ile Arugbo: A ò yánjú ọ̀rọ̀ láàrin ara wa, a ò fẹ́ ilé ẹjọ́ mọ́. - Ìdíle Saraki, ìjọba Kwara
Adeọla mu ẹnu le oniruuru oun ti oju oun atawọn ọdọbinrin ọmọ orilẹede Naijiria miran n ri lori owo nọbi ti wọn n fi wọn ṣe ni ilẹ okeere.
- Àwọn agbébọn pa olóyè ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ìpínlẹ̀ Oyo sínu ilé
- 'Danfo', 'Okada', 'K-leg' àtàwọn ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ti wọ́n fi kún Oxford Dictionary lọ́dun 2020
- Àwọ́n kan ń ràgà bo Diezani nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì láti jẹ́jọ́ ní Nàíjíríà àmọ́ á gbe wá - EFCC
- 'Slay Mama' ni mí; mò dẹ̀ tún ń fọ mọ́tò tà- Bunmi Opakunle
- Gbogbo ọba alayé, tó fi mọ́ Ọọ̀ni àná, Sijuwade ló mọ̀ pé mo fẹ́ jẹ Mayegun - Wasiu Ayinde
- Ṣé lóòtọ́ ni pé ẹ̀wà jíjẹ máa ń jẹ́ kí èèyàn ga? Mubaraq dáhùn ìbéèré yìí