Oxford English Dictionary: 'Àwọn ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ti wọ́n fi kún un lọ́dun 2020

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ní ọdun 2020 ni Oxford English Dictionary ṣe afikún àwón ọ̀rọ̀ tuntun omíràn sínú ìwé náà.
Awọn ọ̀rọ̀ náà to jẹyọ nínú èdè Yòrúba, Hausa, Pidgin.
Awọn ọ̀rọ̀ náà ni ìtumọ àti bi wọ́n se ń sọ nínú èdè gẹ́ẹ̀sì, Buka / tẹria, guber, agric, ember Months, next tomorrow, Kannnywood.
- Àwọn agbébọn pa olóyè ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ìpínlẹ̀ Oyo sínu ilé
- Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ènìyàn lo ti sọnù nítorí àìsàn Iba Lassa ní Kano àti Ondo
- Àṣìta ìbọn sọ́já pa ẹgbọn Kamsi tó pé sọ́ja kó wá fìyà jẹ aládùúgbò rẹ̀
- Àwọn olùgbé Tarkwa Bay ń fọ́ ọ̀pá epo, jí epo ta, la ṣe lé wọn - Iléeṣẹ́ Ológun
- Inú ìbànújẹ́ ni mo wà lórí ikú alága CAN tí àwọn Boko Haram pa- Buhari
Sef, chop, chop-chop, to eat money, barbing, salon, gist, to gist, put to bed, tokunbo, to rub minds àti àwọn ǹkan míran.
Oxford lóri ayelujara rẹ̀ sàlàyé pé bi Naijiria ṣe n fi kun èdè Gẹ̀ẹ́sì ju gbogbo àwọn èdè àgbáye míràn lọ.
Ilé iṣẹ́ náà ni àwọn lo lárá ọ̀rọ̀ ti onkowe Naijiria kan Chimamanda Ngozi Adichie sàlàye pé àwọn èdè ti òun kọ wà lárá ìrírí to ti ri ni Naijiria.
Oxford ni gẹ́gẹ́ bi Chimamanda ṣe sọ, ìgbàgbọ́ wà pé yóò fi iyọ si èdè Gẹ̀ẹ́sí gẹ́gẹ́ bi àwọn ṣe n koju mọ sísọ èdè gẹ̀ẹ́si àye òde òní.
Bí àwọn ọ̀rọ̀ náà àti ìtumọ wọ́n ṣe lọ rèé nínú Iwe ìtumọ Oxford English Dictionary
- Ọ̀gá ọlọ́pàá tó wà ní 'Check Point' kàgbákò ikú òjijì lọ́wọ́ awakọ̀ l'Eko
- Ara gbígbóná, èébì, ara ríro, àti àwọn àpẹẹrẹ mìrán tí ibà Lassa máá n fihàn
- Ààrùn ‘Coronavirus’: Ẹ yé rìnrìn àjò lọ sí ìlú Wuhan mọ́
- Olanrewaju Bamidele fi 'Screw driver' gún ìyáwo rẹ̀ pa
- Ibà Lassa bàlẹ̀ sí ìpínlẹ̀ Enugu! Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ló bẹ̀rẹ̀ ọṣẹ́, Ẹ̀mí kan ti nù















