Oshiomole: Elijah Ayodele ti sọ̀rọ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀dún lórí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ lẹ́gbẹ́ APC

Àkọlé fídíò, Prophecy 2020: Adeboye àti Ayọdele sọ nípa ọjọ́ ìwájú 2020

Iyipada ijọba ọrọ Boko Haram ati bẹẹ bẹẹ lọ jẹ jade

Afiwe aṣotẹlẹ ọdun 2019 ati awọn ọna to fi ṣẹlẹ n jẹ ki ominu kọ awọn miran si ti ọdun 2020.

Pasito Enoch Adeboye ti ijọ RCCG ati Primate Ayodele ti ijọ INRI Evangelical sọ ohun ti wọn ri nipa 2020.