2019 in Retrospect: Àwọn ǹkan tí mi ò rí ṣe ní 2019 ni mo ma fi bẹ̀rẹ̀ 2020
2019 ṣe igba, 2019 se awo igba nkankan baba isasun. Orin to wa pa a to kun un lohun ti awọn eeyan to ba BBC Yoruba sọrọ ṣe lalaye fun gbogbo eniyan.
"Àwọn ǹkan tí mi ò rí ṣe ní 2019 ni mo ma fi bẹ̀rẹ̀ 2020".Ipinu nla kan niyii latẹnu ọgbẹni kan ti a ba sọrọ.
Ẹlomiran gbagbọ pe pẹlu apẹrẹ ti wọn n ri. oun ti wọn ba dawọle ma ṣee ṣe.
"Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀rù ń ba àwọn èèyàn pé Nàìjíríà máa pín, ko ṣi ri bẹẹ.
Ẹ gbọ́ latẹmu awọn ọ́lọ̀rọ̀ gangan.