Illegal Rehab Centre: A le ni ogójì tí wọ́n n kó sinú ìyará kékeré kan níle Ọlọrẹ
Wọn mu mi wa sibi nitori pe mo n mu siga- ọmọbinrin kan.
Leyin ti gomina Seyi Makinde ti ko awọn eeyan to wa ni imuninigbekun kuro lọdọ Aafa Olọrẹ nitosi Ọjọọ nilu Ibadan nipinlẹ Ọyọ Ẹ̀yin òbí, ẹ má kó àwọn ọmọ yín lọ síbùdó atúnwàṣe mọ́ - Seyi Makinde ni BBC ṣabẹwo sibẹ.
Kekere kọ nike Ramọ ni oun ti oju awọn eeyan n ri nile yii.Àṣírí ígbèkùn nílé Olore n‘Ibadan kìí ṣe tuntun, ó ti kọ́ wáyé ní 2008
Oriṣiiriṣii ẹsun ni awọn ọdọ ti wọn ko sinu ile ibaniwi yii fi kan Aafa Olore atawọn to n tọju wọn nibẹ.
Sibẹ awọn miran ninu wọn gba pe iyatọ ti de ba igbesi aye awọn nitori pe ti iya ba to iya fọmọde, o maa yipada ni tipa ni.
- A gbọ́dọ̀ ṣewàdìí ìròyìn ayélujára kí a tó pin in- OloriSuperGal
- Mi ó lè na apá mi àmọ́ mo lè lo ọpọlọ mi fí kọrin-Ayeyi
- Ò bá mi lójijì bí wọ́n ṣe yọ Sẹnetọ Adeyeye bÍi jìgá- Gomina Fayemi
- Ọmọ ogun Nàìjíríà mẹ́wàá dèrò ọ̀run lẹ́yìn ìkọlù ẹgbẹ́ Boko Haram
- 'Màálù tó bá tàsẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ níwájú ilé mi, ó dẹran àsun!"