You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Yoruba Film: Ta ló leè dúró s'ẹ́gbẹ̀ẹ́ Okunnu láì rẹ́rìn ín?
Laipe Okunnu ṣe ọjọ́ ibi, iyen Wale Akorede ti ọpọ eniyan mọ si Okunnu latara gbogbo ere ẹfẹ rẹ to ma n ṣe.
Gbajumọ ni laarin awọn oṣere Yoruba, o si jẹ ọmọ bibi ilu Ibadan ni ipinlẹ Oyo.
Wọn bi i lọjọ Karun, oṣu Kọkanla ọdun 1967.
Ẹwẹ, ati ilu Oyo ati Ogbomoṣo lo ti dagba, to si bẹrẹ si ni ṣe ọmọkunrin.
- Kíni ẹ mọ̀ nípa àwọn gbajúgbaja Yollywood?
- Ta ló lè ṣe ẹ̀fẹ̀ tó Mr Latin láàrin àwọn apanilẹ́rìín fíìmù Yorùbá?
- K-unle Afolayan sọ̀rọ̀ sókè nípa nípa sinimá Anikulapo
- Ẹnikẹ́ni tó ń lo pátákó alákọ̀ọ́lé "No parking" ń fi gbaga òfin ṣeré - Ọlọ́pàá Nàìjíríà
- -Ọkọ mi kò ráyè wọ ojú ara mi láti já ìbálé lẹ́yìn oṣù kan ta ṣe ìgbéyàwó-
- Òͅnà tí àwoͅn onísͅòwò POS ń gbà lu àwoͅn ènìyàn ní jìbìtì rèé – Onísͅòwò POS sͅàlàyé
Nipasẹ molumọọka oṣere Muyiwa Ademola lo fi bẹrẹ si ni gbayii, ti ipa to n ko lati da ẹrin pa oṣonu si tun mu u da yatọ.
Oṣere Yollywood ni Wale Akorede, to kawe gboye ni ile ẹkọ akọṣẹmọṣẹ ti ilu Ibadan.
Ko to dara pọ mọ awọn oṣere, okoowo ni Wale n ṣe, to maa n lọ si Saudi lọ ko aṣọ lati wa ta lorilẹede Naijiria.
- Òͅnà tí àwoͅn onísͅòwò POS ń gbà lu àwoͅn ènìyàn ní jìbìtì rèé – Onísͅòwò POS sͅàlàyé
- Orílẹ̀èdè Kenya àti South Africa ti kéde ìgbésẹ̀ físà ọ̀fẹ́ láàrin ara wọ́n
- U.S Midterm Elections- Buhari kí àwọn ọmọ Naijiria tó jáwé olúborí nínú ètò ìdìbò ilẹ̀ Amẹrika kú oríire
- Ẹnikẹ́ni tó ń lo pátákó alákọ̀ọ́lé "No parking" ń fi gbaga òfin ṣeré - Ọlọ́pàá Nàìjíríà
- Ṣ-é lóòtọ́ ni àwọn jàndùkú kọlu Atiku àti ikọ̀ ìpolongo rẹ̀ ní Borno-
Ọdun mẹtala lo fi ṣe owo aṣọ tita ko to wa papa kara bọ ere tiata. Lara awọn ere rẹ naa lo ti gba orukọ ori itage rẹ, Okunnu.
Ẹ o le wo ere rẹ ki gbogbo agbegbe kan dakẹ ṣuu, a fi ki ẹ rẹrin ni gbogbo ibi to ba ti farahan.
Baale ile ni Okunnu jẹ fun iyawo atawọn ọmọ rẹ.
- Funke Akindele, oníròyìn, agbẹjọrò àti òṣèré; ohun tí ẹ kò lérò nípa rẹ̀
- Tope Oladiji ní Ondo ti dèrò ilẹ̀ẹjọ lẹ́yìn tó ń dúnkookò láti ṣekúpa Bàbà rẹ pẹ̀lú àdá
- 'Nigeria Immigration Services' ṣàlàyé ìdí mẹ́rin tí wọ́n fi da òṣìṣẹ́ 8 dúró tí wọ́n si kìlọ̀ fún àwọn 18 míràn
- Kunle Afolayan, òṣìṣẹ́ báńkì tẹ́lẹ̀ kó tó di gbajúgbajà òṣèré
- I-gbákejì olórí ẹgbẹ́ Ilana Ọmọ Oodua kọ̀wé fi ipò sílẹ̀
- Tinubu fí MC Oluomo sínú ìgbìmọ̀ ìpolongo ìdìbò Ààrẹ
- Kí ló ń fa ìjà láàrin ọba Iragbiji àti Ẹ̀rọ̀ Àríkẹ́, gbajúmọ̀ Oníṣègùn ìbílẹ̀ l’Osun-
- Ọlọ́pàá fí èsì ìwádìí ikú ọmọ Davido, Ifeanyi Adeleke síta..-