Ìdí ti àwọn kọmísọna ṣe to láti kí ìyáwó gómìnà tuntun káàbọ̀

Oríṣun àwòrán, Shaharudeen Galaje
Ọkan nínú àwọn tó dúro sí pápakọ ofurufu láti gba ìyáwo tuntun ọmọ Lẹbaniisi tí Gomina Bauchi ṣẹṣẹ fẹ́ sàlàyé pé kò sí ǹkan ti awọn ń se ju pé àwọn ń tèle àṣà àti ìṣe.
Àgbẹ̀nusọ fún gomina Bauchi Bala Mohammed Mukhtar Gidado, sọ fún BBC pé kò sí ǹkan to buru ninu ki àwọn alába siṣẹ gomina lọ pade ìyàwó rẹ̀ ni pápákọ ofurufu àti pé àṣà ní
Agbẹnusọ lori ọ̀rọ̀ ìròyìn, ń fèsi lóri fọto kan to gba ayelujara opo twitter kan nípa bi àwọn kọmisona ṣe ń duro de ìyàwọ tuntun ti gomina Bala Muhammed ṣẹsẹ fẹ
- Ayẹyẹ igbeyawo melo ni Aarẹ Buhari lọ?
- Kíkọ́ ẹ̀kọ́ gboyè nínú iṣẹ́ ìṣègùn ìbílẹ̀ yóò pèsè ìtọ́jú tó péye fọ́mọ Nàìjíríà- Ẹgbẹ́ àwọn dókítà
- Àtúnṣe òpópónà Lagos-Ibadan àwọn ọ̀ná míràn ti e lè gba
- EFCC gba ọkọ ayọ́kẹ́lẹ́ 30, òògùn ìbilẹ̀ àti ọ̀pọ̀ fóònù lọ́wọ́ àwọn gbájúẹ̀
- Gómínà Bauchi kí olùdíje PDP tó fẹ̀yìn rẹ̀ janlẹ̀
- Iwa nabi tu igbeyawo ọgbọn ọdun ka
" Kiìí ṣe gomina lo ni kí a wá dúro de ìyàwó olun , à wá fun ra wa lá gbàá léro láti ṣe bẹ́ẹ̀ pàápaá julọ láti pàde rẹ̀ ni pápákọ ofurufu"
Iyawo gomina ni, ẹni ọwọ sì ni, àsà wa ni lati bu ọlá fun gẹgẹ bi òṣìṣẹ́ gomina. Kò si ǹkan ti àwọn ènìyàn le sọ, kò si ọ̀rọ̀ to tóbi kankan nínú ọ̀rs to wa nilẹ̀ yìí.

Oríṣun àwòrán, Shaharudeen Galaje
Natasha Mariana ní ìyàwo tuntun ti Gomina Bauchi ṣẹṣeẹ fẹ́, o si dé si ìlú Bauchi fún ìgbà àkọkọ lẹ́yìn ti wọ́n ṣe ìgbéyàwo ní opin ọ̀sẹ̀ to kọkja
Kìí ṣe gomina Bauchi ni ẹni akọkọ ti yóò gbe ìyawo tuntun ninu àwọn gomina to ṣẹṣẹ gori alef, Gomina ìpínlẹ̀ Yobe Maimala Buni yan aya tuntun lẹ́yin ọjọ kini to wọle gẹ́gẹ́ bi gomina, ọmọ gomina àná ni ìpiínlẹ̀ rẹ̀ náà sì lo fẹ́..
Bakan náà lọmọ sori ní Zamfara, bi gomina àna nibẹ Ahmed Sani ṣe fẹ́ ọmọ ọdun mẹ́rindinlogun to jẹ́ ọmọ orilẹ̀-èdè Egypt gẹ́gk bi ìyàwo kẹta ko to kurò lori oye.

Oríṣun àwòrán, Efem












