Buhari: Àwọn ọmọ Nàìjíríà faraya lórí Ìrìn-àjò ààrẹ lọ sí Jordan

Aworan aarẹ Buhari

Oríṣun àwòrán, @NGRPresident

Àkọlé àwòrán, Lẹyin ti aarẹ Buhari ba pari ipade tan ni Jordan,yoo tẹsiwaju lọ si Dubai ni UAElati kopa ninu ipade miran
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Iriwisi ọtọọto lo n tele ikede ti ileeṣẹ aarẹ Naijiria fi si oju opo Twitter wọn pe aarẹ Buhari n lọ si orileede Jordan fun ipade.

Bi awọn kan ti ṣe n ki pe ko ni asọkal ayọ lawọn kan n faraya pe aarẹ Buhari fi ina si ori orule lawọn ipinlẹ bi Zamfara.

Wọn ni o yẹ ki o mu oju to wahala to wa nile ki o to sọ gbera lọ si ipade nita.

Ipade ti aarẹ Buhari n lọ ṣe la gbo pe o ni ohun ṣe pẹlu awọn orileede to wa ni aarin ila oorun agbaye ati awọn ti ariwa ilẹ Afrika.

Nibi ipade naa, ileeṣẹ aarẹ ni aarẹ Buhari yoo ṣepade ti yoo mu agbega ba ọrọ aje Naijiria pẹlu awọn olori ile iṣẹ ati olori orileede lagbegbe naa.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Awọn Gomina ipinlẹ mẹta,Yahaya Bello Kogi,Abiola Ajimobi ati Gomina Abubakar Badaru Jigawa yoo kọwọ rin pẹlu aarẹ́ Buhari.

Buhari ṣẹṣẹ dari irinajo kan si orileede Senegal ni nibi ti wọn ti bura wole sipo fun aarẹ Macky Sall.

Ati irinajo Senegal ati eyi to ṣẹsẹ n lọ yi, ko si eleyi to dun mọ awọn ara ilu kan ninu.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

@Nasirmagori sọ pe inu awọn ko dunsi bi aarẹ́ ko ṣe kọbi ara si ipenija aabo to n ba awọn eeyanipinlẹ Zamfara finra

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Ṣugbọn awọn kan fi ikini ranṣẹ si Buhari ti wọn si gbadura pe ki o gunlẹ layọ

Skip X post, 6
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 6

Awọn kan na ọwọ awada si aarẹ ti wn si bere pe ṣe o ranti fi owo kalẹ ti wọn yoo fi toju ile

Skip X post, 7
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 7

Lọjọ kejilelogun Osu Kẹta ọdun 2018,aarẹ Buhari ṣe abẹwo si ipinlẹ Zamfara nigba ti o n lọ kaakiri awọn ipinlẹ ti ikọlu ti waye kaakiri orilẹede Naijiria.

Abẹwo naa waye lasiko igba ti wahala awọn jaguda to n jin eeyan ati maalu gbe peleke lagbegbe naa.

Lati igba naa di asiko yi,ijọba Buhari ko ti ribi koju ipenija aabo ti o n ba awọn eeyan agbegbe ariwa Naijiria finra.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: