Ọmọ Nàíjíríà: Ó yẹ kíjọba gbé ìgbẹ́sẹ̀ akin lásti dẹ́kun ìpànìyàn

Abule

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló ti pàdánù ẹ̀mí wọn ní Zamfara l'ọ́dún 2018.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Awọn ọmọ Naijiria ko ti i dakẹ lori ipe wọn si ijọba apapọ lati wa atunṣe ti yoo wa lailai si iṣẹlẹ iṣekupani to n waye nipinlẹ Zamfara.

Ọpọlọpọ lo ti fi ohun wọn sita loju opo Twitter lọjọ isinmi lati fi aidunnu wọn han si bi "ọpọlọpọ eniyan ṣe ti padanu ẹmi wọn ni ipinlẹ Zamfara lati igba ti ọdun 2018 ti bẹrẹ."

Awọn kan ni ki ijọba apapọ ṣe iru akitiyan to ṣe si ipaniyan to n waye l'awọn ibomi i ni Zamfara naa.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Awọn kan bu ẹnu ẹtẹ lu Aarẹ Muhammadu Buhari pe 'ko ni ko awọn ọlọpa ati ọmọ ogun lọ si ipinlẹ Zamfara bo ṣe ko wọn lọ si Ekiti lasiko eto idibo gomina to waye nibẹ.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Wahala eyi to waye kẹhin lọsẹ to kọja mu ki awọn eniyan kan padanu ẹmi wọn, t'ọpọlọpọ si di alainilelori nitori bi awọn onikupani naa ṣe dana sun awọn ile wọn l'awọn abule kan mejidinlogun nijọba ibilẹ Zurmi.

Ẹwẹ, ìṣẹlẹ iṣekupani naa ti mu ki ogunlọgọ eniyan maa fi ibugbe wọn silẹ ki wọn o maa ba tun sẹ kongẹ iru iṣẹlẹ bẹ mọ.